Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Àwọn Akọ̀ròyìn Pè Fún Ìròyìn Tí Kò Ní Ẹja-n-bákàn Nínú Lórí Ètò Òsèlú

Àrọwà ti wá fún àwọn akọ̀ròyìn láti jẹ́ olóòtọ́ọ́ àti fún ìròyìn tí ó se déédé nínú ètò ìdìbò àpapọ̀ tí ó ń bọ̀.   Ààrẹ ẹgbẹ́ náà Chris Isiguzo pe ìpè náà ní ìlú Èko, nígbà tí ó ń ṣí…

Ìjọba Àpapọ̀ Sọ Òpópónà Tuntun Di Lílò Fún Mùtúmùwà Ní Ìpínlẹ̀ Plateau

Ìjọba orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti fi òpópónà oní kìlómítà méjì tí ó sẹ̀sẹ̀ parí lé àwọn alákòsóo ilé ìwé gíga Yunifásitì Ìlú Jos, ìpínlẹ̀ Plateau lọ́wọ́ fún lílò.   Níbi ayẹyẹ sísí òpópónà…

Mínísítà Orílẹ̀ Èdè Rwanda Tẹ́lẹ̀ Rí Fi Ẹ̀wọ̀n Jura Látàrí Ìwà Àjẹbánu

Ilé ẹjọ́ gíga orílẹ̀ èdè Rwanda ti ju mínísítà tẹ́lẹ̀ rí fún orílẹ̀ èdè náà  tí ó wà fún Àṣà àti Àmójútó àwọn Ọ̀dọ́ sí ẹ̀wọ̀n ọdún márùn-ún látàrí ìwà àjẹbánu.   Ìròyìn fi yéwa pé, wọ́n dá…
button