Ìjọba orílẹ̀ èdè Uganda ti setán láti gbẹ́ kàǹga epo rọ̀bì alákọ̀kọ́ọ́ irúu rẹ̀ ní pápá Kingfisher.
Ìrètí wà pé, ní ọdún 2025, orílẹ̀ èdè náà yóò máa pèsè àgbá epo tí ó lé ní bílíọ̀nù kan.
Àrídájú fi yéwa pé, Àrẹ Yowei Museveni ni yóò se ìfilọ́lẹ̀ iṣẹ́ náà.