Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹka Akọ̀ròyìn Lórí Eré Ìdárayá Ti Ìpínlẹ̀ Kwara Yan Àwọn Adarí Tuntun

0 110

Ẹka tí ó ń kọ ìròyìn lórí eré ìdárayá ti ìpínlẹ̀ kwara yan àwọn adarí tuntun tí yóò máa tukọ̀ ẹgbẹ́ náà fún ọdún mẹ́ta gbáko.

 

Wọ́n ṣe ìbúra fún àwọn olóyè náà lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n yàn wọ́n sípò.

 

Yíyan alága ẹgbẹ́ náà wáyé pẹ̀lú ìfigagbága láàrin Ayọdeji Ismail ti ilé iṣẹ́ ẹ̀rọ asọ̀rọ̀mágbèsì ti ìpínlẹ̀ kwara àti Ọlayinka Owolẹwa, tí Ayọdeji sì jáwé olúborí.

 

Igbákejì alága àpapọ̀ ẹgbẹ́ náà ti ẹka Ilà Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà, Seun Ajayi, ẹni tí ó sàkóso ìyànsípò náà sọ pé, ètò náà lọ ní ìrọwọ́-rọsẹ̀.

Leave A Reply

Your email address will not be published.