Take a fresh look at your lifestyle.

Davido Di Olórin Àkọ́kọ́ Ní Nàìjíríà Tó Kọ́kọ́ Gbégbá Orókè Nínú -Ẹ̀rọ Ayélujára Instagram ‘Likes’

Oǹkọrin Afrobeats orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Davido tún ti ṣe àseyege gẹ́gẹ́ bí olórin àkọ́kọ́ tí àwọn ènìyàn ẹgbẹ̀run kọ́kọ́ tẹ mo fẹ́ràn rẹ̀ ‘Likes' sórí ẹ̀rọ ayélujára Instagram. Dídé tó padà dé lákọ sórí ẹ̀rọ ayélujára, ó fi…

Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Se Ìfilọ́lẹ̀ Ìpolongo Ètò Ìbò Ní Ìpínlẹ̀ Kano

Ẹgbẹ́ òṣèlú PDP se ìfilọ́lẹ̀ Ìpolongo èto Ìbò ní Ìpínlè Kano, ìwọ̀ Oòrùn Àríwá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọn syì gbé àsìá ẹgbẹ́ fún àwọn olùkópa kọ̀ọ̀kan tí wọn ńlọ fún ipò kan tàbí òmíràn nínú ẹgbẹ́ látàrí ìbò ọdún tó n bọ̀…
button