Oǹkọrin Afrobeats orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Davido tún ti ṣe àseyege gẹ́gẹ́ bí olórin àkọ́kọ́ tí àwọn ènìyàn ẹgbẹ̀run kọ́kọ́ tẹ mo fẹ́ràn rẹ̀ ‘Likes’ sórí ẹ̀rọ ayélujára Instagram.
Dídé tó padà dé lákọ sórí ẹ̀rọ ayélujára, ó fi àwòrán tó rẹwà ara rẹ̀ àti ìyàwó rẹ̀ Chioma sórí ẹ̀rọ ayélujára eléyìí tó mú kí inú àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ dùn jọjọ síi fún ìpadà bọ̀ rẹ̀.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply