Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Spain Yọ “VAT” Kúrò Lórí Oúnjẹ

0 137

Orílẹ̀-èdè Spain ń gbé ìgbésẹ̀ àrà ọ̀tun láti yọ owó Orí Kúrò lórí àwọn oúnjẹ tó se kókó bí burẹdi, mílíìkì àti jẹ́kí ọrọ̀ ajé dẹ̀rọ̀ látàrí ogún Russia ni ìlú Ukraine.

 

Aarẹ Pedro Sánchez ló kéde èyí nínú ọ̀rọ̀ òpin ọdún.

 

Ìjọba tún sọ wípé àwọn yóò ge “VAT” Kúrò láti ìdá mẹwàá nínú ọgọ́ọ̀rún. sí márùn un nínú ọgọ́ọ̀rún .

Ó sọ pé ètò náà wà láti dáàbòbo àwọn òṣìṣẹ́ tó wà lágbegbe méjì àti àwọn tó ń ṣiṣẹ́ lójú méjèèjì nípasẹ̀ àwọn nkàn tó ń wọ́n gógó kí ayé leè dẹrùn.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave A Reply

Your email address will not be published.