Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Gómìnà Nínú Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC SE Ìpàdé Pọ̀ Pẹ̀lú Àjọ Òṣìṣẹ́ Ti Ẹgbẹ́ Oṣèlú APC

Gómìnà méfà, láti inú ẹgbẹ́ òṣèlú APC ati awọn ọmọ ẹgbẹ́ olupolongo ìbò aarẹ nínú ẹgbẹ́ kan naa ti wa ninu Ipade pẹlu Àjọ Òṣìṣẹ́ Ti ẹgbẹ́ APC . Ipade náà n waye ni gbọ̀ngàn ìpàdé ti ẹgbẹ òṣèlú APC ní Abuja. . Alága gbogbo gbò fún…

Ajíbádé Yóò Ṣáájú Ikọ̀ Falcons Nígbàtí Wọ́n Bá Dojúkọ Nadeshiko Ní Ìlú Kobe

Ògbóntarìgì agbábọ́ọ̀lù Ajíbádé yóò ṣáájú Ikọ̀ tí àwọn Obìnrin orílẹ̀-èdè yìí nígbà tí wón bá fesẹ̀wonsẹ̀ pẹ̀lú ojúgbà wọn láti orílè-èdè Japan ní ọjó Ọjọ́rú ní Ìlú Kobe. Ara ẹlẹṣẹ̀ ayò, Onome Ebi ṣẹṣẹ n bọ̀ sipò látàrí ifarapa tó ní…

Ààrẹ Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Àwọn Ológun Fún Ìdásílẹ̀ Àwọn Tí Wọ́n Kó Nígbèkùn

Ìgbìmọ̀ eléni méje tí ààrẹ ti olórí ikọ̀ ti aabo elétò awọn ọmọ ogun látọwọ́ CDS Ogágun Lucky Irabor ti ríi dájú pé wọ́n dá ènìyàn mẹ́tàlélógún tókù sílẹ̀ nínú ìṣẹ̀lẹ̀ ìkóni ní gbèkùn ti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Boko Haram ní ọ̀nà Abùjá ṣí…

Ẹgbẹ̀rún Márùn Ó Lé Díẹ Ọmọ Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC Darapọ̀ Mọ́ Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ní Ìpínlẹ̀ Kogi

Ó lé ní Ẹgbẹ̀rún márùn Ọmọ Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC tí wọn lọ darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ oṣèlú alátakò PDP ní Ìpínlè Kogi báyìí. Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú APC ní ọjó Àìkú ní Avrugo àti wọ́ọ̀dù tó múlé tìwọn, ní agbègbè ìbílẹ̀ ìjọba Igalamela/Odolu ti ìpínlẹ…

Àjọ Tó Ń Sọ Nípa Bójú Ọjó Se Rí Ti Rọ Àwọn Àgbẹ̀ Orílè-èdè Yìí Láti Ka Ìwòye Ọ̀rọ̀ Ojú Ọjọ́ Sí

Àjọ to ń sọ nípa bóju Ọjó se rí (NiMET) ti Orílè-èdè yìí ti sọ pé bí àwọn àgbẹ̀ ṣe ń pàdánù ọ̀pọ̀ irè oko lórílẹ̀ èdè yìí kò sẹ̀yìn àìka ọ̀rọ̀ àjọ náà tó sọ̀rọ̀ nípa bójú ọjó se rí sí. Adarí ẹ̀ka ti ojú ọjọ́ NiMET , Ògbẹ́ni Adélékè…
button