Adẹ̀yìnmú Ẹgbẹ́ Agbábáọ̀lù Algeria, Bedrane Kòní Leè kópa Nínú Ìdíje Ọlọ́rẹ̀ẹ́sọ̀rẹ́ Pẹ̀lú Ikọ̀…
Adeyinmu ẹgbẹ́ agbábáọ̀lù Algeria, Abdelkader Bedrane kòní leè kópa ninu Idije
Ọlọ́rẹ̀ẹ́sọ̀rẹ́ pẹ̀lú ikọ̀ tí Super Eagles orílè-èdè Nàìjíríà.
Bí ìròyìn se ròó lórí wẹ́búsáìtì ti Algeria Football Federation, ọmọ ọgbọ̀n ọdún náà fi…