Take a fresh look at your lifestyle.

Àna ọmọbìnrin Ààrẹ Bùhárí Jáde Pẹ̀lú Ipò Kíní Ní Fáfitì Ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì

0 66


Àna ọmọbìnrin Ààrẹ Bùhárí, Mrs Zahra Bùhárí ti jáde pẹ̀lú Ipò Kíní ní Fáfitì kan ní ìlú ọba -UK.

Ó jáde pẹ̀lú ipò kínní nínú ìmọ̀ ẹ̀kọ́ Architectural Science.

Aya Ààrẹ, Aisha Buhari ló sọ eléyìí di mímọ lórí ẹ̀rọ ayélujára social media ní ọjó ìṣẹ́gun.

Bákannáà, ní odún mẹ́ta sẹ́yìn, aya Ààrẹ ṣàfihàn aworan àwọn ọmọ rẹ̀ tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣetán ní àwọn ifáfitì ní ìlú ọba- United Kingdom.

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.