Take a fresh look at your lifestyle.

Dídé Uzoho Àti Ebube Sí Ìpàgọ́ Jẹ́ Kí Gbogbo Àwọn Tí Wọ́n Fìwépè Pé Pérépéré  

0 61

Francis Uzoho àti Ebube Duru ti darapọ̀ mọ́ àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn tí wọ́n wà ní Ìpàgọ́ fún ìdíje ọlọ́ọ̀rẹ́sọ̀rẹ́ pẹ̀lú orílè-èdè Algeria.
Gbogbo àwọn mẹ́rìnlélógún tí wọ́n fìwépè ni wọ́n ti dé pẹ̀lú àwọn méjèjì tó ṣẹ̀ṣẹ̀ dé.
Àwọn agbábọ́ọ̀lù náà nìwọ̀nyí:

Maduka Okoye, Francis Uzoho, William Troost-Ekong, Kenneth Omeruo, Chidozie Awaziem, Ola Aina, Calvin Bassey, Zaiducaptain Ahmed Musa,  Sanusi, Kevin Akpoguma, àti Ozoronwafor.

 

Àwọn  yókù ni: Wilfred Ndidi, Raphael Onyeka, Alex Iwobi, Frank Onyedika, Moses Simon, Taiwo Awoniyi, Chidera Ejuke, Dessers, Terem Moffi, Ademola Lookman, Adebayo, Gift Saviour àti Ebube Duru.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.