GBÈSÈ ORÍLẸ ÈDÈ NÀÌJÍRÍÀ TI WỌ TIRILIỌNU NAIRA-NBS
Gbèsè tí àwọn ìpínlẹ̀ àti ìjoba àpapọ̀ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà ní àjọ tó n rí sí ètò ìsírò lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, National Bureau of Statistics (NBS) ti ní ó ti lé ní tiriliọnu mẹ́tàlélọ́gbọ̀n naira…