Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí pinnu pé òhun yóò pèsè ààbò tó péye

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

176

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti mu dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè lójú pé, gbogbo làásìgbò tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí ní orílẹ̀-èdè yóò tó di àfìsẹ́yìn téégún ń fisọ.

Gomina Ipinle Zamfara, Bello Matawalle ṣe ifitonileti naa nibi ifọrọwanilẹnuwo pẹlu awọn oniroyin olu Ile  ni ọjọ ọjọọru, lẹhin ti o ti jabọ  fun Aarẹ Buhari lori ipo aabo ni Ipinlẹ rẹ.
Matawalle, ti o yìn iṣẹ takuntakun ti awọn ile iṣẹ aabo ti  ipinlẹ rẹ n ṣe, tun sọ pe aabo to peye yoo wa  fun awọn agbe lati da oko wọn.

Leave A Reply

Your email address will not be published.