Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò bẹ̀rẹ̀ sí ní máa gbà lára èrè lori àwọn amáyédẹrùn àgbáyé àti ilé-iṣẹ́ ayélujára

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

27

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣetán láti lo òfin tó fún ìjọba lágbára láti gba owó -orí lára èrè  orí àwọn amáyédẹrùn àgbáyé àti àwọn ilé-iṣẹ́ ayélujára tó ṣe pàtàkì sí ọrọ̀ ajée Nàìjíríà.

Alaye kan lati Ọfiisi  Igbakeji Aare ni ọjọ aiku sọ pe ,Yemi Osinbajo tọka si awọn ọrọ wọnyi ati awọn omiiran lakoko ti o n sọrọ pẹlu aṣoju  ẹgbẹ to n mojuto gbigba owo-ori [CITN] Taxation of Nigeria, ti Alakoso rẹ, Mr Adesina Adedayo bẹwo ni ọjọ ẹti to kọja. ni Ile-iṣẹ Aare.

Gẹgẹ bii Ijọba apapọ,  fifikun osunwọn owo ori rẹ lasiko yii ko ni da lori ofin isuna 2019,  o ti ni agbara tẹlẹ lati feẹ  owo-ori lapapọ loju, eyiti o pẹlu gbigba owo-ori lara owo to n wọle fun orilẹ -ede lori awọn ohun amayedẹrun agbaye ti o ṣẹ pataki si ọrọ aje ilẹ yii,kooda boya wọn  ko tii ṣe idasilẹ ile-iṣẹ tabi wọn ti da silẹ rẹ  ati pe wọn ko san owo-ori lọwọlọwọ ni Naijiria bayi.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.