Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti ṣetán fún ìyẹ̀wò àtúńyẹ̀wò ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ kejì -Ilé iṣẹ́ ààrẹ
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Ìjoba Nàìjíríà sọ pé òhun ti ṣetán fún àjọ tó ń rí sí ìdàgbàsókè ìlú adúláwọ̀ láti sàtúńyẹ̀wò ẹlẹ́gbẹ́ kejì orílẹ̀-èdè ara ẹni.
Agbẹnusọ fun aarẹ, Femi Adesina ṣe afihan eyi ni ọjọọru, lakoko ti o n ṣalaye fun Awọn oniroyin olu Ile, ni opin ipade igbimọ ijọba apapọ ti ọsẹ yii,ti aarẹ Muhammadu Buhari ṣe adari rẹ. O sọ pe Aare Buhari ti fọwọsi pe ki ayẹwo naa ko maa waye nibi ipade Igbimọ Alaṣẹ apapọ ọlọsọọsẹ.
Agbẹnusọ fun aarẹ ṣe akiyesi pe, ọpọlọpọ ilọsiwaju ti wa, laarin igba ti o ṣe ayẹwo to kẹhin ati lọwọlọwọ bayi.
Leave a Reply