Orílè èdè south africa ti fowọsi àtìlẹ́yìn fún ilé-isé irin, ẹ̀ka ti ìsòwò àti ti ìdíje.
Ijọba ati awọn ti ọrọ kan ti fọsi owo to le ni ẹẹdẹgbẹfa biliọnu fun eto idagbasoke irin.
ọna mẹfa ni ijọba pin ipinnu ti wọn se lati mu eto idagbasoke ba ile-isẹ ni orile ede naa, lara wọn ni lati maa tun irin rọ ati eyi ti yoo mu eto irọrun ba ọna lati maa mu awọn ohun elo irin wọle ati jade, lati orilẹ ede Afirika.
Awọn igbimọ marundinlọgbọn ni wọn yoo maa mojuto eto awọn osisẹ irin , ti awọn osisẹ ile-isẹ ijọba yoo maa samojuto wọn.
Leave a Reply