Take a fresh look at your lifestyle.

GBÈSÈ ORÍLẸ ÈDÈ NÀÌJÍRÍÀ TI WỌ TIRILIỌNU NAIRA-NBS

Ademọla Adepọju

44

Gbèsè tí àwọn ìpínlẹ̀ àti ìjoba àpapọ̀ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà ní  àjọ tó n rí sí ètò ìsírò lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, National Bureau of Statistics (NBS) ti ní ó ti lé ní tiriliọnu mẹ́tàlélọ́gbọ̀n naira (N33.11trillion (NBS).

Ìpínlẹ̀ Èkó ni ó ní gbèsè tí ó pọ̀jù , nígbà tí ìpínlẹ̀ Jigawa naa si tẹ̀le nípa gbèsè tí wọ́n yá lọ́wọ àwọn ilé-isẹ́ aladaani.

 

 

 

 

HAMZAT ROSHIDAT

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.