Take a fresh look at your lifestyle.

Ìyanṣẹ́lódì àwọn dókítà: A ti Ṣe àṣeyọrí tó nítumọ̀ -–Mínísítà ètò Iṣẹ́

Ìjọba orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà sọ pé òhun ti yanjú gbogbo àwọn nǹkan  tí àwọn dókítà Oníségùn ń bèèrè fún, àyàfi èyí tí ó lòdì sófin “kò sí iṣẹ́  kò sáwó”. Nitorinaa, ijọba n kepe awọn ọmọ ẹgbẹ dokita…

Ààrẹ Bùhárí já ìdè lọ́pọ̀lọpọ̀ – Adésínà

Olùdámọ́rán pàtàkì fún ààrẹ lórí ìròyìn àti  ìkéde,Fẹ́mi Adéṣínà,sọ pé,ààrẹ ti ṣe àṣeyọrí tó tayọ t’àwọn  ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ lórí àkójọ èrè Ilé -iṣẹ́ tó ń ṣàkóso ọ̀rọ̀ Epo ní Orílẹ̀ –èdè Nàìjíríà…

Ààrẹ Bùhárí yọ mínísítà ètò ọ̀gbìn àti mínísítà fún iná mọ̀nà –mọ́ná ńipò

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí   kéde àtúntò ráńpẹ́ nínú àwọn  mínísítà rẹ̀, tí èyí sì bá mínísítà mẹ́rin. Meji ninu awọn mẹrẹẹrin naa ni lati fi ipo silẹ ti meji si lọ di ipo miran mu. Awọn to yọ nipo ni…

Ìjọba orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà fi owó ìràǹlọ́wọ́ lórí epo sínú Ìsúná 2022

Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti sọ pé kí àwọn ará ìlú máá fòyà,kí wọ́n sì máá bẹ̀rù lórí fífikún owó epo pẹtiróò,ó sọ pé owó ìràǹlọ́wọ́ lórí epo petiróò ti wà nínú ìsúná ọdún 2022. Oludari…

Ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn jẹ́ ìjọba Nàìjíríà, àjo àgbáyé lógún púpọ̀

Ìjọba orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà ti bẹ̀rẹ̀ ìfọwọ́sowọ́pọ̀ tuntun pẹ̀lú  ètò àjọ àgbáyé ní orílẹ̀ -èdè, láti mú  ìlọwọ́sí bá  ẹ̀tọ̀ ọmọnìyàn ní orílẹ̀ -èdè náà. Ninu ijiroro kan ti wọn filọlẹ ni Ilu Abuja ni…

NIDCOM gbóríyìn fún aṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àkọ́kọ́ ní Ọsirélíà

Àjọ tó ń ṣàkóso ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ Nàìjíríà tó ń gbé lókè òkun,NIDCOM,ti kí aṣojú rẹ̀ àkọ́kọ́ ní Ọsirélíà kú oríi re. Alaga  Igbimọ naa, Abike Dabiri-erewa ninu ifiranṣẹ ikini ku oriire  kan, ki Abiola Akinbiyi lori…

Ènìyàn méjì- lé- lọ́tà- lélọ́ọ̀dúnrún míràn tún ti ní ààrùn covid

Ní ọjọ́ àìkú,ọjọ́ kọkàn – dín – lọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ,ọdún 2021, àwọn ènìyàn méjì- lé –lọ́tà –lélọ́ọ̀dúnrún míràn tún ti ní ààrùn covid, gẹ́gẹ́ bí ilé – iṣẹ́ tó ń mójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ṣe kéde rẹ̀ ní…
button