Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Násáráwá ti ní kí ìgbìmọ̀ ìjọba rẹ̀ lọ rọ́kún sílẹ́

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

113

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Násáráwá, Abdullahi Súlè ti tú Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ Ìpínlẹ̀ náà ká.

Gomina ipinlẹ naa ni o ṣe  ikede ituka naa nibi  ipari ipade awọn alaṣẹ   pẹlu Awọn oludamọran Pataki, ati Awọn Oluranlọwọ Pataki Agba. Otun ni ki awọn oluranlọwọ pataki rẹ naa o  lọ rọ kun sile.

Gomina Sule dupẹ lọwọ awọn igbimọ oṣiṣẹ  ati awọn oluranlọwọ rẹ, fun  ifarada wọn ati ipa ti wọn ko nipa aṣeyọri  iṣakoso iṣejọba naa  titi di akoko yii.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.