Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí já ìdè lọ́pọ̀lọpọ̀ – Adésínà

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

99

Olùdámọ́rán pàtàkì fún ààrẹ lórí ìròyìn àti  ìkéde,Fẹ́mi Adéṣínà,sọ pé,ààrẹ ti ṣe àṣeyọrí tó tayọ t’àwọn  ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ lórí àkójọ èrè Ilé -iṣẹ́ tó ń ṣàkóso ọ̀rọ̀ Epo ní Orílẹ̀ –èdè Nàìjíríà NNPC, tí ó tún jẹ́  Mínísítà fún , ní ìgbà àkọ́kọ́ ní ọdún mẹ́rìnlé-lógójì.

Femi Adesina, sọ pe aarẹ, fun idi eyi, ti ṣe nnkan tawọn aṣiwaju rẹ ṣeti  lori ile-iṣẹ to n mojuto eto epo ilẹ  NNPC, ni ọpọlọpọ ọdun sẹyin, bakannan, o tun ja awọn ide   miiran.

O sọ pe: “ide nla kan ti o ja  laipẹ ni ti Ile-iṣẹ to n mojuto ọrọ Epo ilẹ  Orilẹ-ede Naijiria (NNPC), to kede èrè rẹ lapapọ, akọkọ iru rẹ ninu itan ile-iṣẹ ọhun ni ọdun mẹrinle-logoji. Labẹ Aarẹ Muhammadu Buhari, ti o tun jẹ  Minisita fun Awọn orisun Epo ilẹ, ile-iṣẹ ọhun kede ere akọkọ iru rẹ  ti o jẹ meétalá- din- lẹ ẹ̀wá- dinlọ́ọ̀dúnrún biliọnu Naira,ni eyi ti ko ṣẹlẹ ri.

‘Ṣugbọn iyẹn kii ṣe ide  pataki kan ṣoṣo ti o ja  ni igbesi aye ijọba Buhari. Wọn pọ. Wọn pọ lọpọ yanturu ti ko si ṣee ka. ”

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.