Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà fi owó ìràǹlọ́wọ́ lórí epo sínú Ìsúná 2022

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

117

Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti sọ pé kí àwọn ará ìlú máá fòyà,kí wọ́n sì máá bẹ̀rù lórí fífikún owó epo pẹtiróò,ó sọ pé owó ìràǹlọ́wọ́ lórí epo petiróò ti wà nínú ìsúná ọdún 2022.

Oludari alamojuto apapọ ile-iṣẹ to n mojuto eto pẹtiro ni orilẹ-ede GMD, NNPC, Ọgbẹni Mele Kyari ṣọ eleyii di mimọ ni  Ọjọbọ, nibi ijiroro itagbangba ọlọjọ mẹta akọkọ  ni 2022 si 2024, Ilana inawo alabọde  (MTEF) & Iwe Ilana Iṣuna (FSP).

Ile -igbimọ apaṣẹ ni o  ṣeto ijiroro itagbangba naa, lati ṣe ayẹwo awọn iwe inawo meji ti o jẹ ipilẹ fun isuna orilẹ -ede lọdọdun.

Ọgbẹni Kyari tun n mun da  awọn ọmọ orilẹ -ede Naijiria loju pe,  awọn alabaṣepọ tun n tẹsiwaju lati mọ akoko ati bi o ṣe dara julọ lati ṣe imunadoko ni idiyele epo pẹtiro PMS, eyiti o duro lọwọlọwọ ni = N = Naira mejile-lọgọjọ (162) fun lita kan.

Gẹgẹbi NNPC GMD,wọn pese owo adinku lori epo  ninu isuna 2022, nitori ko han gedegbe pe ilọwọsi awọn alabaṣepọ yoo pari ṣaaju ki ọdun 2022 to pin si mẹrin .

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.