Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Tag

Nigeria Government

Nàìjíríà Gbá Àwọn Ọmọ Rẹ̀ Ọgọ́rùn-Àti-Mẹ́jọ Látí Orílẹ̀-èdè Niger

Ìjọba Nàìjíríà tí gbá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè ọgọ́rùn-ún àti mẹ́jọ tí há mọ́ orílẹ̀-èdè Niger ní Pápá kọ òfurufú Murtala Mohamed International, ní Ìlú Èkó, Gúúsù Ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà. Ipadabọ náà jẹ́ iṣẹ́ Ìjọba Àpapọ̀ ní Ìfọwọ́sowọ́pọ̀…

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Ọ̀rọ̀ – Ọ̀rọ̀ ìdágbére Láti Ẹnu Ààrẹ Muhammadu Buhari, Ààrẹ Orílẹ̀-Èdè…

Ẹ̀yin ènìyàn mi lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, àti àwọn tó ń gbé káàkiri àgbáyé. Mò ń bá a yín sọ̀rọ lóní, èyi tó jẹ́ iṣẹ́ mi tí ó gbẹ̀yìn gẹ́gẹ́ bi Ààrẹ Ìjọba tiwa-n-tiwa tí a yàn sípò gẹgẹ bi ààrẹ orilẹ-ede…

Ẹ̀ka Ọkọ̀ Òfurufú Nàìjíríà Gbà Owó Tó Lé Ní Ọ̀ọ́dẹ́gbẹ̀rin Mílíọ̀nù Náírà Fún Ìtọ́jú Pápákọ̀

Ilé-iṣẹ́ Òfurufú tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Ọjọ́rú gbá ibuwọlú ìwé iṣẹ́ àkànṣe tí ó tó ọ̀ọ́dẹ́gbẹ̀rin lé lógún mílíọ̀nù Náírà N721m fún ìtọ́jú Pápákọ̀ Òfurufú Aminu Kano International ní Ìpínlẹ̀ Kano, Àríwá Ìwọ̀-oòrùn tí orílẹ̀-èdè yìí tí…
button