Browsing Category
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
This is a category for world news
Orílẹ̀-èdè Ísráẹ́li Ṣe Ìkọlù Láti Inú Òfurufú Sì Àwọn Ibìkan Ní Hezbollah
Àwọn ọmọ ogún Israẹlì ti ṣe Ikọlu láti ojú ofurufu ti o pe ni ''Hezbollah targets'' ní gúsù Lẹbaloni lẹyin ti ti wọn ti ju àwọn ohun ìjà olóró láti ààlà lẹyin ti idaduro ogún ti jẹ kí agbegbe náà dúró gbari tẹlẹ.
Ilẹ̀…
Ilé Ẹjọ́ Germany Buwọ́lu Èròngbà Merz Láti Yáwó Tabua
Ilé ẹjọ ní Germany ti buwọ́lu ètò Merz láti lò owo ìlú tó pọ̀ àti èròngbà ìyáwó rẹ̀ pẹlu ọnà láti ma fi àye gba àwọn Ẹgbẹ oselu alatako.
Ipinu yìí fún ilé aṣòfin ní ààyè láti joko se ìpàdé ní ọsẹ tó nbọ láti gbé ètò Olubori eto…
Àjọ Adarí Ilẹ̀ Adúláwọ̀ Fẹ́ Dá Ọọ̀ni Ti Ilé Ifẹ̀ Lọ́lá
Ẹlẹ́kẹrìnlá irú rẹ àjọ ipade ẹyẹ Adari ilé Adúláwọ̀ tí wọ́n gbékalẹ̀ lábẹ́ àjọ UN International Peace Governance Council (UNIPGC), ẹ̀ka ilẹ̀ Adúláwọ̀ yóò fi àmì ẹyẹ ọlọlá- Grand Commander of Peace fún Ọba Adeyeye Babatunde Enitan…
Ìpàdé Pẹ̀lú Putin Ńso Èso Rere-Putin
Ààrẹ Amẹ́ríkà ti sọ ní ọjó Ẹtì pé ogún ilẹ̀ Russia àti Ukraine leè pari lẹyin Ìpàdé Washington pẹlu ààrẹ Russia, Vladimir Putin tó wáyé ní ọjó Ọjọ́bọ̀.
'' A ní ìpàdé tó so èso rere pẹlu ààrẹ Vladimir Putin ni ọjó Ọjọ́rú, oore…
Àjọ Iṣọkan Agbaye Bèrè Fún Àlàyé Ìtẹ Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn Lójú Mọ́lẹ̀ Ní Àárín Gbùngbùn Ilẹ̀ Olómìnira
Àjọ Ìṣọ̀kan Àgbáyé ti bèrè fún ẹtọ ni Aarin Gbungbun Ile Olominira-Central African Republic (CAR) lẹyin ọpọlọpọ ìtẹ ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn lójú mọ́lẹ̀ ti àwọn agbofinro se. Ọ́fíìsì ajọ UN to n ja fún ẹtọ Omoniyan àti MINUSCA ti eleto…
Ènìyàn Mẹ́tàdínlógójì Ta Téru Nípàá Nínú Ìjàmbá Ọkọ̀ Ní Bolivia
Ọkọ̀ méjì kọlu ara wọn èyí tó fa ìjàmbá ọkọ̀ tó lágbára ti ènìyàn Mẹ́tàdínlógójì sí di olóògbé ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ èniyàn sí farapa ni ìwọ̀ oòrùn àgbègbè Potosi, ọlọ́pàá àtí alàkóso ìbílẹ̀ sọ èyí.
Ìṣẹlẹ náà wáyé ní àárò kùtù ní ọ̀nà…
Hackman Ọmọ Orílẹ̀-èdè America Àti Ìyáwó Rẹ̀ Ní Wọ́n Bá Òkú Wọ́n Nílé
Òṣèré ọmọ Orílẹ̀-èdè America tó gbá amí ẹyẹ 'Oscar' Gene Hackman ní wọ́n bá òkú rẹ̀, tí ìyàwó rẹ̀ Betsy Arakawa àti ajá wọ́n ní ilé wọ́n ní Santa Fe, New Mexico.
Hackman tí ló tó ọgọ́ta ọdún Nínú iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́bí òṣèré, Ó gbá àwọn…
Isreal, Palestine Ṣé Pàṣípààrọ̀ Àwọn Òkú Àti Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n L’ójúnà Látí Fopin Sí Ogún
Isreal àti Palestine tí ṣé pàṣípààrọ̀ àwọn àpótí Òkú mẹ́rin kán tó jẹ́ tí àwọn ọmọ Israel tó kú sínú túbú, bí àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Palẹ́síténì tí wọ́n tí mọ́ ẹ̀wọ̀n àti àwọn tó wá ní atimọle tí gbá itu sílẹ ní Gaza àti àwọn tí 'West Bank'…
Wọ́n Gbà Obìnrin Ọmọ Amẹ́ríkà Kan Mú Fún Ìpànìyàn Ọmọ Kékeré Jòjòló Ní Paris
Wọ́n ti gbá ọmọbìnrin ilẹ̀ Amẹ́ríkà ti kò ti pé ogún ọdún kan mú ní ìlú Parisi látàrí júju ọmọ kékeré Jòjòló tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ bí láti ojú fèrèsé ilé itura sita tí ọmọ náà sì kú. Olùpẹ̀jọ́ àti ilé Iṣé ìròyìn Faransé ló sọ èyí.…
Ilẹ̀ Amẹ́ríkà Sọ Pé Òun Kò Jáwọ́ Atìlẹ́yìn Fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ti sọ pé àjosépò òun pẹlú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà si gun régé àti pé ètò ìrànwọ́ ti òun nse fún un sì wà síbẹ̀ sùgbọ́n òun ń se ètò àgbéyẹ̀wò olósù mẹ́ta láti jẹ́ ki gbogbo rẹ̀ túbọ̀ dára síi ni.
Ètò àgbéyẹ̀wò…