Browsing Category
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
This is a category for world news
Amẹ́ríkà Gbé Òté Lé Àwọn Kan Fún Títẹ Ojú Òfin Mọ́lẹ̀
Ẹka ilẹ̀ Amẹrika to n rí sí ètò nipa owo ti sọ pe àwọn ti gbe ote le awọn ajọ mẹta kan to wa ni United Arab Emirates (UAE) pẹlu ọkọ̀ aképo kan to forukọ silẹ lati ọdọ ilẹ̀ Liberia nipa títè ojú ofin mọlẹ lori owo ori epo ilẹ̀…
Orílẹ̀-èdè Lebanoni Àti Iraq Tẹwọ́bọ Ìwé Àdéhùn Alajọsepọ̀ Fún Ìmúgbòrò Ètò Ọ̀gbìn
Orílẹ̀-èdè Lebanoni àti Iraq ti tọwọ́bọ iwe adehun alajọsepọ fún imugbooro etò ọ̀gbìn, àjọ ìgbìmọ̀ ti Mínísítà ilẹ̀ Lebanoni sọ èyí.
Iroyin ro pe, wọn tewobọ iwe adehun náà ni ilu Beirut láti ọwọ́ Mínísítà ètò ọgbin ilẹ̀…
Ukraine: Zelenskiy Se Àbẹ̀wò Sí Ikọ̀ Ológun Lójú Ìjà
Aare Volodymyr Zelenskiy tí se abẹwo sí àwọn ọmọ ogun Ukrain ni agbegbe iwaju Gusu Ìla-oorun, o si fun won ni ami ẹyẹ.
Agbẹnusọ rẹ sọ pé, o wá sí itòsí ibi ti awọn ologun ati alatako won ti n dana ibon koju ara wọn ní apá iwaju…
South Korea Pé Aṣojú Ìlú Russia Lórí ìbáwí Ààrẹ
South Korea tí ránṣẹ pé àwọn aṣojú ìjọba Orílẹ̀-èdè Russia láti gbọ́ èròngbà wọ́n lórí bí Ààrẹ Yoon Suk ṣé bú ẹnú atẹ́ lú ìyìn tí Orílẹ̀-èdè Russia ń ṣé fún North Korea lórí ṣiṣé òun ìjà olóró kàn, ilé-iṣẹ́ Ilẹ̀ Òkèèrè sọ.
Chung…
India Yóò Rọ́pò Àwọn Ọmọ Ògún Ní Maldives Ní Oṣù Kàrún
India yóò kó àwọn ọmọ ogún rẹ̀ kúrò ní Maldives ní Oṣù kàrún ùn ọdún, Ilé-iṣẹ́ ilẹ̀ Òkèèrè Maldivian sọ́.
Èyí wáyé lẹyìn tí àwọn orílẹ̀-èdè méjèèjì ṣé àdéhùn lórí kíkó àwọn Ológun náà kúrò.
Àwọn ọmọ ogún náà tó dúró ní etikun India…
Myanmar Dá Àwọn Ọdaràn Mẹ́ta Pàdà Sí China
Myanmar tí fí àwọn ọdaràn ọmọ Orílẹ̀-èdè China mẹ́ta pàdà sílùú Beijing, àwọn tí wọ́n ń fí ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè náà ṣé ẹrú ní ilẹ̀ Òkèèrè láti máa lọ́ní lọ́wọ́ gbà.
Bai Suocheng, Wei Chaoren àti Liu Zhengxiang ló ṣé…
Nadezhdin Ṣetán Láti Gbé Iná W’ojú Putin Nínú Ìdìbò Ààrẹ Tó Ń Bọ́
Boris Nadezhdin sọ pé oún tí gbá àwọn ifọwọ́sí àwọn aráàlú látí dije nínú ìdìbò tó ń bọ̀ ní Russia.
Ẹní tó jẹ́ alága Ìgbìmọ̀ àgbègbè tẹ́lẹ̀ rí tí dì ìlú mọọkà bó ṣé dúró bí alátakò fún ìṣàkóso Ààrẹ Putin àtí ti ìkọlù rẹ̀ sí Ukraine.…
Ikọ̀ Ọmọ Ogun Ikọ̀kọ̀ Israẹli Pa Àwọn Agbébọn Mẹta Ní Agbègbè West Bank
Ikọ̀ Ọmọ Ogun Ikọ̀kọ̀ Israẹli alagbara to dibon bí ọmọ Palestine ti pa awọn agbebon Meta danu ni ile iwosan kan ni West Bank, Ọlopàá ati awọn ologun sọ eyi.
Iroyin ro pe, wọn fi ẹsùn kàn okan lara wọn pé o n ṣètò Ikolu ojiji,…
Ẹ yógun jà – Aṣojú Palestine bẹbẹ
Aṣojú Palestine sí Nàìjíríà, Abdullah Muhammad Shawesh, ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí gbogbo àgbáyé àti àwọn onínú ire ènìyàn láti ri pé ogun Gaza wá sí òpin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.
Nigba ti o n ba awọn oniroyin sọrọ ni Eko nibi iba awọn…
Ilé-ẹjọ́ Àjọ Àgbáyé Pàṣẹ Fún Israel Látí Dènà Ipànìyàn Ní Gaza
Ilé-ẹjọ́ gíga tí Àjọ Àgbáyé pàṣẹ fún Israel látí yàgò fún àwọn ìpànìyàn ní ipá-kú-pá ní Gaza, ṣùgbọ́n kò mú ẹnu bá ìdádúró ogún.
Àwọn onídájọ́ ní Ilé-ẹ̀jọ́ Àgbáyé náà ṣé ìdájọ náà ní Orílẹ̀-èdè South Africa fún Israel.
Riyad…