Browsing Category
Uncategorized
Bí Eré Bí Eré, Super Falcon Dásọ Ìyà Fún Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù Australia Pẹ̀lú Àmì Ayò Mẹ́ta Sí Méjì
Àfi bí àlá, Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù Australia to jẹ ara àwọn ikọ̀ ti gbogbo ayé bẹ̀rù jùlọ ti jẹẹ́ sára wòtòwòtò láti ọwọ́ àwọn Ikọ̀ Super Falcon
Super Falcon ò wá ṣeré rárá lóríi pápá, Bó tilẹ̀ jẹ́pé Australia ló kọ́kọ́ mi àwọ̀n ní Isẹju…
Owó Epo Lọ Sókè Lalá Sí Ẹ̀tàdínlógún-le Lẹ́gbẹ̀ta Náírà Ní Nàìjíríà
Owó Epo lọ sókè lala si ẹ̀tàdínloógún le Ẹgbẹ̀ta Náírà ni gbogbo ìlú ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti àwọn ènìyàn si ń san ẹgbẹ̀ta-(₦600) Náírà láti nǹkan bi òjì lẹ lẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta Naira-(₦540) tẹle fún Jala Lítà epo kan.
Ní ìbẹ̀rẹ̀…
Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Kano Buwọ́lu Ogún Olùgbani Nímọ̀ràn Fún Gómìnà
Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Kano Buwọ́lù
tí buwọ́lu ẹ̀bẹ̀ Gómìnà Abba Kabir-Yusuf
fún ògún olùgbani nímọ̀ràn pàtàkì.
Abẹnugan ilé ìgbìmọ̀, Ọ́nọ́rébù Ismail Falgore ló kaá sí eti ìgbọ́ ìgbimọ̀ ni ibi ìpàdé náà ni ọjọ́…
Àjọ UBEC Gbóríyìn Fún Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara Fún Àtìlẹ́yìn Rẹ Lórí Àwọn Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba.
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara ni àjọ UBEC ti Gbóríyìn fún látàrí iṣẹ takuntakun rẹ nípa awọn ilé ẹ̀kó ìjọba
Wọn gbé ọ̀sùbà o káre fún pẹ̀lú ipá ti o ń kọ pẹ̀lú ilé iṣé ẹ̀kọ́ ti ìjọba láàrin àsìkò pè rète ti won dá ilé ẹ̀kó ìjọba náà sílẹ̀.…
Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Tọ́ Yan Oúnjẹ Ṣíṣẹ̀ Láàyò Fẹ́ Dáná Láti Ko Mílíọ̀nù kan Náírà Jọ Fún Àwọn…
Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó Yan Oúnjẹ Ṣíṣẹ̀ Láàyò tó sì wọ ìwé àgbáyé Guiness Record, Hilda Baci, yóò fì ẹbùn dìdáná oúnjẹ rẹ hàn ní ọjọ ẹtì ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kejẹ láti ko owó jọ fún àwọn opó.
Oúnjẹ ṣíṣẹ̀ náà ni Joseph Edger, àgbà òjé…
Adarí Àgbà pátápátá Fún Àwọn Òṣìṣẹ́ Ṣe Ìdánilékọ̀ọ́ Nípa Ààbò Fún Àwọn Òṣìṣẹ́.
Adarí àgbà pátápátá fún àwọn òṣìṣẹ́ ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí bẹ̀rẹ̀ ìdánilékọ̀ọ́ nípa ààbò fún àwọn ìjọba.
Adarí àgbà pátápátá náà Folashade Yemi-Esan nigba ti o n sọ̀rọ̀ ní ìlú Abuja, sọ pé ìdánilẹ́kọ̀ọ́ náà wa ni ìbámu pẹ̀lú òfin àti…
Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Bù Ẹnu Àtẹ́ Lù Ìyọnísẹ́ Àwọn Òṣìṣẹ́ Ìjọba Ní Ìpínlẹ̀ Benue
Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP bù ẹnu àtẹ́ lù Ìyọnisẹ́ àwọn Òṣìṣẹ́ Ìjọba tí wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ gba sise ní Ìpínlẹ̀ Benue láti ọwọ́ Gómìnà Hyacinth Alia.
Gómìnà Alia ló dédé sọ pé kí òṣìṣẹ́ tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ gbà tó ju ẹgbẹ̀rún mẹ́ta lọ, lọ rọ́kú nílé.…
Ìyàwó Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ábíá Se Àbẹ̀wò Sí Àwọn Tó Bá Ara Wọn Ní Ilé Iṣẹ́ Òwò Ọmọ Òòjọ́ Òfegè
Ìyàwó Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ábíá, Ìyáàfin Priscilla Otti, ní ọjọ́ Ìṣẹgun bẹ àwọn obìnrin aláboyún ọ̀dọ́mọdé mọ́kànlélógún wò tí orí kó yọ kúrò ní ilé ìṣẹ́ òwò ọmọ tí ó wà ní Umunkpei, Nvosi ní ìjọba ìbílẹ̀ Isialangwa, ìpínlẹ̀ Ábíá.
Ó…
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Ọ̀rọ̀ – Ọ̀rọ̀ ìdágbére Láti Ẹnu Ààrẹ Muhammadu Buhari, Ààrẹ Orílẹ̀-Èdè…
Ẹ̀yin ènìyàn mi lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, àti àwọn tó ń gbé káàkiri àgbáyé.
Mò ń bá a yín sọ̀rọ lóní, èyi tó jẹ́ iṣẹ́ mi tí ó gbẹ̀yìn gẹ́gẹ́ bi Ààrẹ Ìjọba tiwa-n-tiwa tí a yàn sípò gẹgẹ bi ààrẹ orilẹ-ede…
Mínísítà Ilẹ̀ Òkèèrè Ti Orílẹ̀-èdè Italy So Àbẹ̀wò Sí Orílẹ̀-èdè Paris Rọ̀
Mínísítà Ilẹ̀ Òkèèrè ti Orílẹ̀-èdè Italy, Antonio Tajani ti so àbẹ̀wò rẹ̀ sí Orílẹ̀-èdè Paris ní ọjọ́ Ọjọ́bọ̀ rọ̀. Ó sọ pé Mínísítà abélé ilẹ̀ Faransé ṣẹ Orílẹ̀-èdè Italy pẹ̀lú adarí ìgbìmọ̀ ìjọba, Giorgia Meloni sọ ọ̀rọ̀ àbùkù tí…