Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÁRAYÀ
This is a category for sport news
Taiwo Awoniyi Àgbábọ́ọ̀lù Ọmọ Nàìjíríà Jí Pàdà Lẹ́yìn Iṣẹ́ Abẹ́
Àgbábọ́ọ̀lù 'Super Eagles' tí Nàìjíríà àti Nottingham Forest tí Orílẹ̀-èdè England, Taiwo Awoniyi, tí jí pàdà lẹ́yìn tó tí ṣiṣẹ́ abẹ́ lẹ́yìn ìpalára ikùn nlá kán tó ní lórí pápá.
Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà náà fí ikùn kọlù ìgi golí ní…
Ikọ̀ Ranger Lu Ikọ̀ Katsina Ní Àlùbami Ayò Mẹ́rin Sí Òdo 4-0
Ní ọjọ́ Àìkú, ikọ̀ Rangers International FC ti ìlú Enugu lu ikọ̀ Katsina United FC ni àlùbami ayò mẹrin sì Odo (4-0) ti wọn kò sì leè ru tùú láti tilẹ̀ da ọkàn soso padà nínú ìdíje ọlọ́sẹ̀ kẹrìndínlógójì ti - Nigeria Premier…
Ìdíje NPFL : Ikọ̀ Ìkòròdú City Lu Ìkọ Bayelsa United Ní Ayò Mẹ́ta Sí Méjì
Ikọ̀ Ikorodu City pakítí mọ́lẹ̀ ní ilé wọn láti lu Ikọ̀ Bayelsa United FC ní àlùbami ẹ̀wà ní ayò Mẹ́ta sí Méjì (3-2) ní ọjọ́ Ọ̀jorú níbi ìdíje alárinrin náà.
Ìdíje ọdún 2024/2025 Nigeria Premier Football League (NPFL) ti ọjọ́…
Bournemouth Yá Arsenal L’ẹnu Nígbàtí Aston Villa Ń Tẹ̀síwájú Lórí Tábìlì ‘EPL’
Bournemouth bóri Arsenal fún ìgbà àkọ́kọ́ nínú ìdíje ilẹ́ Gẹ̀ẹ́sì 'English Premier League' ní Ọjọ́ Sátidé (Àbámẹ́ta), àti pé ìkọ náa túnramú ní ìdàkejì ìfẹ́sẹwọ́nsẹ́ ná èyí tó yá àwọn ènìyàn l'ẹ́nu bí wọ́n ṣé bóri pẹ̀lú ayo méjì sí ẹyọ kan…
Ìpínlẹ̀ Anambra Ṣègbékalẹ̀ Ẹgbẹ́ Imọlẹ̀ Ìṣọ̀kan Ìdárayá
Gómìnà Chukwuma Soludo tí ṣé ìfilọ́lẹ̀ ẹgbẹ́ imọlẹ̀ ìṣọ̀kan ìdárayá ní Awka ní ìpínlẹ̀ Anambra, gẹ́gẹ́ bí ará ètò eré ìdárayá tí orílẹ̀-èdè ikejilelogun, èyí tí wọ́n pé ní 'Gateway Game,' tí yóò wáyé ní Ìpínlẹ̀ Ogun látí ojọ́…
Ẹgbẹ́ Àwọn Ọdọ Olùwẹ̀ Ọmọ Nàìjíríà Dé Sí Egypt Fún Ìdíje
Ẹgbẹ́ ọdọ Nàìjíríà tí dé sí Orílẹ̀-èdè Egypt fún ìdíje ọdọ ilẹ̀ Áfíríkà ní Egypt tí a ṣètò fún ọjọ́ kọkandinlọgbọn oṣù kẹ́rin sí ọjọ́ kẹ́ta oṣù karùn-ún ọdún 2025.
Ẹgbẹ́ náà tó ní àwọn olùwẹ̀ mẹ́rinlá (14), àwọn ọmọkùnrin mẹjọ (8)…
CAF Kéde Àwọn igbákejì Ààrẹ tuntun níbi ìpàdé ìgbìmọ̀ Aláṣẹ
Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ (EXCO) fún Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ́lù Láfíríkà (CAF) ti ṣe ìpàdé ní Accra, Ghana, ní ọjọ́ Àbámẹ́ta ṣíwájú ìfigagbága eré bọ́ọ́lù àṣekágbá àwọn ilé ẹ̀kọ́ Agbábọ́ọ́lù Láfíríkà CAF.
Aarẹ…
Tani Yóò Jáwé Olúborí Láàrín Al Ahly Àti Sundowns Nínú Ìdíje CAF
Al Ahly àti Mamelodi Sundowns tí ṣetán ìfẹ́sẹ́wọsẹ́ kán ní alẹ́ ọjọ́ Ẹtì ní pápá ìṣèré 'Cairo International' bí wọ́n tí n ja fún ayé níbi ìparí eré-ìdárayá tí 'CAF Champions League.'
Ìfẹ́sẹ́wọsẹ́ àkọkọ́ ní 'Pretoria' parí ní ọ̀mì,…
Ìpínlẹ̀ Enugu Gbá Imọlẹ̀ Ìṣọ̀kan Ìdárayá Tí Orílẹ̀-èdè
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Enugu, Peter Mbah, tí gbá imọlẹ̀ ìṣọ̀kan tí èrè ìdárayá àpapọ̀ (National Sports Festival), l'àkókò tó ṣé ìlérí ìkópa kíkún tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tí ìpínlẹ̀ rẹ̀ nínú èyí tó mbọ, tí yóò wáyé ní Ìpínlẹ̀ Ogun, Nàìjíríà.
Mbah,…
Wọ́n Sin Òkú Balógun Ikọ̀ Rangers Tẹ́lẹ̀ri, Isiadinso Ni Ìpínlẹ̀ Anambra
Wọ́n ti sin Òkú Balógun Ikọ̀ Rangers Intl FC ti Enugu tẹ́lẹ̀rí ní ọjó Ojoru ní ìlú rẹ, Obeagu Osili. Njikoka, ìjọba ibilẹ Anambra, ipinlẹ Anambra.
Agbabọ́ọ̀lù teleri náà ló jẹ balogun iko Rangers laarin odun 1981 sì 1984, o ku ni ojo…