Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÁRAYÀ
This is a category for sport news
2023 U20 AFCON: Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù Flying Eagles Yóò Ní Ìpàgọ́ Ìgbáradì Ní Òkè-òkun Ní Oṣù Kínní
Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù Flying Eagles yóò ni Ipagọ́ Ìgbáradì ní Òkè-òkun bẹ̀rẹ̀ ní ìparí oṣù kínní ọdún yìí látàrí ìdíje 2023 U20 AFCON.
Eléyìí di mímọ̀ láti ẹnu akọ́ni-mọ̀ọ́gbá wọn- Ladan Bosso. Ó sọ wípé NFF fẹ́ ní ìpàgọ́…
Paris 2024 : Orílẹ̀-èdè Tunisia Yóò Gbàlejò.
Ni igbaradi fún eré ìdíje lorisirisi ọ̀nà lórí papa ti Paris 2024, àjọ àgbáyé ilé áfíríkà ti fọwọ́ sí kí orílẹ̀-èdè Tunisia gbàlejò àwọn orílẹ̀-èdè láti figagbága fún ìdíje náà .
Orílè-èdè Tunisia yóò gbelejo idije ẹlékẹ́tàlá irú rẹ, ni…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ògùn bẹ̀rẹ̀ àtúnṣe pápá ìṣeré MKO Abíọ́lá
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ògùn,gúsù-iwọ̀-oòrùn Nàìjíríà, ti bẹ̀rẹ̀ àtúnṣe pápá ìṣeré káríayé MKO Abíọ́lá,ní olú-ìlú rẹ̀, Abẹ́òkúta láti pèsè ìtura fún àwọn olùwòran.
Ọ̀gá àgbà akọ̀wé fún ìròyin sí…
CAF Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Ìdíje Bọ́ọ̀lù Àwọn ilé-ìwé Ní Áfíríkà
Gẹ́gẹ́ bí ọnà látí ró àwọn Ilé-ìwé àti àwọn ọmọ akẹkọ lágbára ní ilẹ̀ Áfíríkà. L'ọ́ṣẹ́ yìí, CAF tí ṣé ìfilọ́lẹ̀ àwọn Ilé-ìwé ní ilẹ̀ Áfíríkà tí wọ́n pé ní "Africa School Football Championship" tí ń ṣé ìwúrí fún àwọn ọdọ.
Ìdíje Bọ́ọ̀lù…
Nàìjíríà Daro Ikú Gbajúgbajà Àgbábọ́ọ̀lù Pele
Ààrẹ Muhammadu Buhari tí dára pọ̀ mọ́ àwọn aṣáájú àgbáyé láti fi ìbànújẹ́ hàn lórí ikú gbajúgbajà agbabọ́ọ̀lù Brazil, Edson Arantes do Nascimento, tí a mọ̀ sí Pele tó kú ní ọjọ́bọ̀.
Àgbábọ́ọ̀lù afẹsẹgba tó tóbi jùlọ́ ní àgbáyé tí kù…
Anthony Joshua Gbé Ìgbésẹ̀ Akin Láti Tẹ̀síwájú
Ẹlẹ́sẹ̀ẹ́ kù bí òjò ọmọ Nàìjíríà, Anthony Joshua sọ wípé òun ti gbáradì fún ìtẹ̀síwájú gẹ́gẹ́ bíi ẹni tí yóò gbégbá orókè jùlọ nínú eré ìdárayá ẹ̀ṣẹ́ jíjà.
Joshua, ẹni tí ó fi iga gbága…
Djokovic Balẹ̀ Gùdẹ̀ Sí Australia Látàrí Ìdíje
Novak Djokovic ti gúnlẹ̀ ṣí ìlú Australia ní ǹkan bí ọdún kan géérégé tí wọ́n dáa padà kúrò ní ìlú náà.ìròyìn ro pé o dé fún ìdíje ẹlẹ́ni mẹ́wàá ti yóò bẹ̀rẹ̀ ní osù tó ń bọ̀ tí wọn n pè ní "Australian Open".
Ó gúnlè…
Orílẹ̀-èdè Belarus Sọ Eléré-ìdárayá Òlímpííkìì Herasimenia Sí Ẹ̀wọ̀n
Ilé ẹjọ́ tó kalẹ̀ sí ìlú Minsk ti sọ eléré-ìdárayá àná, awedò, Aliaksandra Herasimenia àti ajajangbara olóṣèlú Alexander Opeykin sì ẹ̀wọ̀n ọdún méjìlá látàrí ìpè tí wọ́n pe láti gbé òté àti ìgbésẹ̀ lé ètò ààbò ìjọba àpapọ…
Àjọ Àgbáyé Àwọn Eléré ìdárayá Tí Dínà Mọ́ Àwọn Eléré Kenya Mẹ́ta Kàn
Àwọn eléré ìdárayá mẹ́ta tí Kenya tí ní idinamọ fún àkókò àpapọ̀ ọdún mẹ́jọ lẹ́yìn tí wọ́n kùnà níbí ìdánwò oògùn - doping.
Ẹ̀ka Athletics Integrity Unit (AIU) tí fi òfin dé aṣáájú eléré-ìje Alice Jepkemboi Kimutai ati Johnstone Kibet…
Ikọ̀ agbábọ̀ọ̀lù Argentina Gbo omi Ewúro Sójú Ikọ̀ agbábọ̀ọ̀lù France Nínú Ìdíje Àsekágbá Ife Àgbáyé
Ikọ̀ ti Argentina tí Lionel Messi jẹ́ Balógun wọn gbo ewúro sí ojú tí alátakò wọn- France ni àkókò wòmí ki n gba sí ọ - Penalty nínú àsekágbá ìdíje ife àgbáyé ti ó tẹnu bepo lánàá.
Balógun ẹgbẹ́ agbábọ́ölù Argentina, Lionel…