Browsing Category
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
This is a category for politics news
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Nasarawa Ṣèlérí Àkànṣe Isẹ́ Amúlúdàgbà Láì Yáwó Kiri
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Nasarawa ti sèlérí àkànṣe iṣẹ amúlúdàgbà lai yáwó kiri ilé ifowopamọ fún ìpínlẹ̀ Nasarawa.
Ó sọ eyi nibi ìtunu ààwẹ̀ Ramadan níbi tó ti gbá àwọn olóyè Egbe oniroyin lalejo-omo Egbe ajo Nigerian Union of Journalists (NUJ),…
Gómìnà Soludo Ń Ṣe Bẹbẹ Ní Ìpínlẹ̀ Anambra- Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin
Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀gbẹ́ni Somtochukwu Udeze ti gbósùbà fún Gómìnà Soludo látàrí àwọn àseyori ọlọ́kan-ò-jọ̀kan tí ó ti wáyé ní ìpínlẹ̀ náà
Nínú àtẹ̀jáde kan tí ó wáyé…
Kọmísọ́nà Mẹ́ta Gba Ìwé Ìjókòósílé Fún Ìgbà Díẹ̀ Ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ebonyi, Francis Nwifuru ti pàṣẹ kí kọmísọ́nà mẹ́ta nínú ìgbìmọ̀ ìsèjọba rẹ̀ rọọ́kún sílé látàrí kíkùnà láti yọjú sí ẹnu iṣẹ́
Àwọn kọmísọ́nà tí ọ̀rọ̀ kàn ní : Solomon Azi…
Ẹgbẹ́ APC Bu Ẹnu Àtẹ́ Lu El-Rufai Látàrí Sísọ Ọ̀rọ̀ Òdì Sí Ìgbésẹ̀ Ìjọ̀ba
Ẹgbẹ́ òsèlú APC ti sàpèjúwe ọ̀rọ̀ òdì tí gómìnà Ìpínlẹ̀ Kaduna tẹ́lẹ̀rí sọ sí ẹgbẹ́ náà nígbà tí ó sọ wípé ẹgbẹ́ náà ti yapa sí òfin àti àlàkalẹ̀, gẹ́gẹ́ bi irọ́ pátápátá, ọ̀rọ̀ tí kò rẹ́sẹ̀ walẹ̀…
Mínísítà Fún Àkànse Isẹ́ Ń Se Takun-Takun – Alẹ́nulọ́rọ̀ Ẹgbẹ́ Òsèlú LP Juwọ́ Káre
Alẹ́nulọ́rọ̀ kan nínú ẹgbẹ́ òsèlú LP ẹka ìpínlẹ̀ Ebonyi, Ọ̀mọ̀wé Emmanuel Ezeh ti sàpèjúwe gómìnà Ìpínlẹ̀ Ebonyi tẹ́lẹ̀rí tí ó tún jẹ́ mínísítà fún àkànṣé iṣẹ́, Onímọ̀-ẹ̀rọ David Umahi gẹ́gẹ́ bí mínísítà…
Adarí Ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Nasarawa Rọ Àwọn Obìnrin Láti Má Fà Sẹyìn Fún ìdàgbàsókè Orílè-èdè…
Adarí Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Nasarawa , Dọ́kítà Jatau, ti pé àwọn Obìnrin Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ko ipá réré ki wọn sí fà sẹyìn fún ìdàgbàsókè Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Jatau to sojú Kokona, sọ èyí di mímọ̀ lásìkò ayẹyẹ àjọ̀dún Eggon…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Se Àtúntò Ìgbìmọ̀ Ìjọba Pẹ̀lú Bíbúra Fún Àwọn Kọmísọ́nà…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara, AbdulRahaman AbdulRasaz ti búra fún Ọ̀mọ̀wé Lawal Ọlọhungbẹbẹ àti Ọ̀mọ̀wé Maryam NnaFatima Imam gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìgbìmọ̀ tuntun
Ó pàrọwà sí wọn láti rí ìyànsípò náà gẹ́gẹ́ bi…
Ẹ Fàdúrà Jagun Fún Ìyànsípò Ààrẹ Tinubu Fún Sá à Ẹlẹ́ẹ̀kejì Lásìkò Ààwẹ̀…
Mínísítà fún Àkànse Isẹ́, Sẹ́nétọ̀ David Umahi ti pàrọwà sí àwọn mùsùlùmí jákè-jádò Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lati gbàdúrà fún ìyànsípò ààrẹ Tinubu fún Sá à ẹlẹ́ẹ̀kejì
Umahi wòye pé nǹkan…
Ilé Asòfin Ìpínlẹ̀ Kwara Buwólu Ìyànsípò Kọmísọ́nà Méjì
Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀, Kwara ti buwólu ìyànsípò Mariam Nna Fatimah láti ìjọba Ìbílẹ̀ Edu àti Ọ̀mọ̀wé Lawal Ọlalekan Ọlọrungbẹbẹ láti ìjọba ìbílẹ Iwọ̀ Òrùn Ilọrin gẹ́gẹ́ bi Kọmísọ́nà ìgbìmọ̀ ìjọba ìpínlẹ̀…
Òtúbáńtẹ́, Ọ̀rọ̀ Tí Kò Rẹ́ṣẹ̀ Walẹ̀ Ni Ẹ̀sùn Tí Sẹ́nétọ̀ Netasha Fi Kan Ààrẹ Ilé…
Ìgbìmọ̀ tí ó wà fún Àtúnṣe Ìwà, Ìfẹ̀sùnkàn ní Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin ti sàpèjúwe ìwé ẹ̀sùn ìfẹ́ni ní ipá àti àsìlò ọ́ọ́fìsì tí Sẹ́nétọ̀ Natasha Akpoti-Uduaghan fi kan Ààrẹ Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin gẹ́gẹ́ bí…