Browsing Category
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
This is a category for politics news
Adari Àgbà pátápátá Fún ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Ki Ààrẹ Tinubu kú ayeye Ọjọ́ ìbí ọdún mẹ́tàléláàdọ́rin.
Adari ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣẹ́nítọ̀ Godswill Akpabio ba Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bola Ahmed Tinubu yọ àyọ̀ ayẹyẹ ọjọ-ibi mẹ́tàléláàdọ́rin.
Nínú àtẹ̀jáde kan láti ọwọ́ Akpabio, ètò ti o buwolu, ṣe àpèjúwe Ààrẹ Tinubu…
Ẹgbẹ́ Òsèlú APC Se Ìpolongo Ìtanijí Ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi
Ẹgbẹ́ Òsèlú APC ti bẹ̀rẹ̀ ìwọlé ní ojúlé sí ojúlé láti ta àwọn alátìlẹyìn, ọmọ ẹgbẹ́ náà jí jákè-jádò ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́tàlá tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi
Alága ẹgbẹ́ náà ti Ìpínlẹ̀ Ebonyi, Stanley…
Àbádòfin Fún Ìdásílẹ̀ Àjọ Elétò Ìdìbò Ti Ìjọba Ìbílẹ̀ Ń Tẹ̀síwájú Ní Ilé…
Àbádòfin fún ìdásílẹ̀ àjọ ìsàkóso ètò ìdìbò sí àwọn ìjọba ìbílẹ̀ gbogbo ni ó ti kọjá ìpele kejì ní ilé asòfin
Àbádòfin náà ní àfojúsùn fún ìdásílẹ̀ àjọ kan fún ìsàkóso ètò…
Àlàkalẹ̀ Tí Ó Dúróore Ní Ọ̀pákùtẹ̀lẹ̀ Ìdàgbàsókè- Akọ̀wé Ìjọba Àpapọ̀
Akọ̀wé Ìjọba Àpapọ̀, Ọ̀mọ̀wé George Akume ti sọ pé àlàkalẹ̀ tí ó peregedé àti mímú iṣẹ́ dé ògóńgó ni yóò mú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dé ilẹ̀ ìlérí
Akume sọ ọ̀rọ̀ náà níbi àpérò àwọn alẹ́nulọ́rọ̀…
Rògbòdìyàn Ọ̀rọ̀ Ìjọba Ìbílẹ̀ Ọ̀sun : Ẹgbẹ́ NULGE Rawọ́n Ẹ̀bẹ̀ Sí Àwọn Òsìṣẹ́ Láti Padà…
Ikọ̀ kan nínú Ẹgbẹ́ NULGE, ẹka tí ìpínlẹ̀ Ọsun ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí àwọn òsìṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ náà láti padà sí ẹnu iṣẹ́ fún ànfààní mùtú-mùwà
Adarí ikọ̀ náà, Ọ̀gbẹ́ni Adebayọ Adekunle…
Alẹ́nulọ́rọ̀ Láti Ààrin Gbìngbìn Ìpínlẹ̀ Cross Rivers Pè Fún Ìdásílẹ̀ Ìpínlẹ̀ Ogoja
Kò dín ní ìjọba Ìbílẹ̀ mẹ́rin ní Ìpínlẹ̀ Cross Rivers tí ó ti ní ìfẹnukò pẹ̀lú ojúgbà rẹ̀ ní àréwá ìpínlẹ̀ náà léyìí tí wọn ń pè fún ìdásílẹ Ìpínlẹ̀ Ogoja
Àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rin náà , Ikom,…
Ilé Asòfin Se Àtìlẹyìn Fún Ìgbésẹ̀ Ààrẹ Látàrí Ìkéde Ìjọba Pàjáwìrì Ní…
Ilé ìgbìmọ̀ Asòfin kejì ti buwọ́lu ìgbésẹ̀ Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu pẹ̀lú ìkéde ìjọba pàjáwìrì tí ó wáyé ní ìpínlẹ̀ Rivers
Wọ́n se àtìlẹyìn fún ìgbésẹ̀ náà lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n gba ìwé àtẹ̀jísẹ́…
Gómìnà Lábẹ́ Ẹgbẹ́ Òsèlú PDP Pàrọwà Sí Ààrẹ Tinubu Láti Yí Ìpinnu Padà Lórí…
Ikọ̀ àwọn Gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú PDP ti gba ààrẹ Tinubu nímọ̀ràn láti yí ìpinnu rẹ̀ padà lórí ìkéde ìjọba pàjáwìrì tí ó wáyé ní ìpínlẹ̀ Rivers
Alága ikọ̀ náà, Gómìnà Bala Mohammed ti…
Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Yóò Se Ìjíròrò Lórí Ìkéde Ìjọba Pàjáwìrì Tí Ó Wáyé Ní…
Àrídájú ti wà pé Ilé Asòfin Àgbà Yóò Se ìjíròrò ní Ọjọ́bọ̀ lórí ìkéde ìjọba pàjáwìrì tí ó wáyé ní ìpínlẹ̀ Rivers, Sẹ́nétọ̀ Jimoh Ibrahim ni ó fí ọ̀rọ̀ náà léde
Alága ìgbìmọ̀ tí ó ń rí…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Nasarawa Ṣèlérí Àkànṣe Isẹ́ Amúlúdàgbà Láì Yáwó Kiri
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Nasarawa ti sèlérí àkànṣe iṣẹ amúlúdàgbà lai yáwó kiri ilé ifowopamọ fún ìpínlẹ̀ Nasarawa.
Ó sọ eyi nibi ìtunu ààwẹ̀ Ramadan níbi tó ti gbá àwọn olóyè Egbe oniroyin lalejo-omo Egbe ajo Nigerian Union of Journalists (NUJ),…