Browsing Category
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
This is a category for politics news
Gómìnà Soludo Se Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Ọ̀dọ́ Ìpínlẹ̀ Anambra
Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀jọ̀gbọ́n Chukwuma Charles Soludo ti pèsè ìrànlọ́wọ́ owó fún àwọn ọ̀dọ́ akẹ́kọ̀ọ́jáde tí kò dín ní ẹgbẹ̀rún márùn-ún fún ìpele alákọ̀kọ́ọ́ tí ìrètí sì wà pé ìpele ẹlẹ́ẹ̀kejì yóò…
Ìgbákejì Abẹnugan Gbóríyìn Fún Ilé Ẹjọ́ Tó Ga Jùlọ Pé Ìjọba Àwarawa Ti Borí
Igbákejì Abẹnugan ilé ìgbìmọ̀ Asojú Sòfin, Ọnarébù Benjamin Okezie Kalu ti kí ààrẹ Bola Ahmed Tinubu kú oríire ìdájọ Ilé Ẹjọ́ tó ga jù ní orílẹ̀-èdè to fi ìdí ààrẹ múlẹ pé òun lo jawe olúborí nínú ìbò ààrẹ tó kọjá
Nínú àkọsílẹ…
Ètò Ìdìbò Ìpínlẹ̀ Imo, Kogi, Bayelsa Se Pàtàkì- Àjọ INEC Sọ̀rọ̀ Sókè
Àjọ INEC fi àrídájú hàn pé òun kò ní fi ọwọ́ yẹpẹrẹ mú ètò ìdìbò tí ó ń bọ̀ lọ́nà, èyí tí yóò wáyé ní ìpínlẹ̀ Kogi, Imo, ati Bayelsa.
Àjọ náà tẹ̀síwájú pé òun yóò siṣẹ́ kára láti ríi…
Ilé Ẹjọ́ Tí Ó Ń Gbọ́ Èhónú Ìbò Fi Ìdí Ìjáwé Olúborí Tambuwal Múlẹ̀ Gẹ́gẹ́ Bí…
Ilé Ẹjọ́ tí ó ń gbọ́ ẹ̀hónú ìbò ní ìpínlẹ̀ Sokoto ti fi ìdí ìjáwé olúborí gómìnà ìpínlẹ̀ naa tẹ́lẹ̀rí, Aminu Tambuwal múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ń sojú Gúúsù ìpínlẹ̀ Sokoto ní ilé ìgbìmọ̀ Asòfin àgbà.…
Lórí Ìrawọ́ Ẹ̀bẹ̀ Atiku Àti Obi Sí Ilé Ẹjọ́: Ilé Ẹjọ́ Àpapọ̀ Ti Setán Láti Fi Ìdájọ́…
Ilé Ẹjọ́ Àpapọ̀ ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni ìrètí wà pé yóò fi ìdájọ́ léde ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n osù kẹwàá lórí ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ tí olùdíje lábẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú PDP, Atiku Abubakar àti ojúgbà rẹ̀ ti ẹgbẹ́…
Ẹjọ́ kò tẹ́milọ́rùn Ìbò ààrẹ: PDP nírètí pé òun yóò yege ní ilé-ẹjọ́ tó ga jùlọ
Ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò Nàìjíríà, Peoples Democratic Party, PDP, ti sọ pé ó dá òun lójú pé ilé-ẹjọ́ tó ga jùlọ yóò ṣe ìdájọ́ òtítọ́ bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ìgbẹ́jọ́ kò tẹ́milọ́rùn ẹ̀yìn Ìbò ààrẹ 2023.
Akọwe apapọ…
Níbi Ètò Ìdìbò Tí Yóò Wáyé Ní Ìpínlẹ̀ Bayelsa, Kogi Àti Imọ, Àjọ Elétò Ìdìbò Se…
Àjọ Elétò Ìdìbò, INEC ti se ìkìlọ̀ fún àwọn ẹgbẹ́ òsèlú láti jìnà sí ìtànkálẹ̀ ìròyìn òfegé síwájú ètò ìdìbò tí yóò wáyé ní ọjọ́ kọkànlá osù kọkànlá ní ìpínlẹ̀ Bayelsa, Kogi àti Imo…
Gómìnà ìpínlẹ̀ Zamfara yan awọn olúṣàkóso fún ìgbìmọ̀ ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́rìnlá
Gómìnà ìpínlẹ̀ Zamfara Dauda Lawal ti buwọ́lù yíyan àwọn olúṣàkóso fún ìgbìmọ̀ ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́rìnlá ní ìpínlẹ̀ náà.
Gomina tun buwọlu yiyan awọn akọwe ati awọn alabojuto igbimọ fun awọn ijọba ibilẹ náà.…
Ilé-ẹjọ́ tí ń gbọ́ awuyewuye ẹ̀yìn ìbò gba ìbò aṣòfin ẹgbẹ́ Labour wọlé, ní ìpínlẹ̀…
Ilé-ẹjọ́ tí ń gbọ́ awuyewuye ẹ̀yìn ìbò ní ìlú Awka, ìpínlẹ̀ Anambra, ní ọjọ́ Ẹtì ti gba ìbò Aṣòfin Victor Afam Ogene wọlé gẹ́gẹ́ bíi ẹni tí ó borí nínú ìbò gbogbogbòò 2023, ní ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú ìjọba…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Dunnú Bi Ashiru Se Di Ìgbákejì Adarí Sẹ́nétọ̀
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara, AbdulRahman AbdulRazaq ti fi idunnu re hàn bi Sẹ́nétọ̀ Lola Ashiru lati ipin agbegbe gusu Kwara se di Ìgbákejì Adari Sẹ́nétọ̀ tuntun ti orile-ede yii.
Gómìnà AbdulRazaq sọ ninu ọrọ re pe, igbega náà tó sì…