Browsing Category
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
This is a category for politics news
Ìdàgbàsókè Àti Ìkópa Àwọn Ọ̀dọ́ Nínú Ìsèjọba Jẹ Ìjọba Lógún- Ayọdele Ọlawande
Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti sàfihàn ìfarajì rẹ̀ fún ìdàgbàsókè àti ìkópa àwọn ọ̀dọ́ nínú ètò ìsèjọba, ìdàgbàsókè ìgbèríko gẹ́gẹ́ bí àwọn ìgbésẹ̀ tí yóò jẹ́ kí àlàáfíà jọba ní Orílẹ̀-èdè…
Ẹ Jẹ́ Kí Ìsọ̀kan Àti Ìdàgbàsókè Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Jẹ Yín Lógún – Ààrẹ Tinubu…
Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti pàrọwà sí ọmọ Nàìjíríà láti wà ní ìsọ̀kan kí wọ́n sì rí i dájú pé Orílẹ̀-èdè jẹ wọ́n lógún nítorí pé ìtẹ̀síwájú Nàìjíríà se pàtàkì ju ohun kóhun lọ
Ààrẹ sọ ọ̀rọ̀…
Ìbò Ọdún 2027: Ọ̀dọ́ Yóò Sàtìlẹyìn Fún Ẹgbẹ́ SDP
Ẹgbẹ́ ọ̀dọ́ ìlọsíwájú ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n n pè ní Alliance for Transformation Mandate (ATM), ti sọ pé àwọn yóò sàtìlẹyìn fún ẹgbẹ́ Social Democratic Party (SDP) látàrí ìbò àpapọ̀ ọdún 2027 tó ń bọ̀.
Ọ̀gá àgbà patapata ẹgbẹ́ náà,…
Igbákejì ààrẹ Bẹ Ìpínlẹ̀ Delta Wò
Igbákejì ààrẹ Kashim Shettima ti gúnlẹ̀ sì ìlú Asaba tii ṣe Olú ìlú ìpínlẹ̀ Delta.
Ìrìn-àjò náà ní ṣe pẹ̀lú Gómìnà ìpínlẹ̀ Delta, Governor Sheriff Oborevwori to dìgbà dẹrulù rẹ̀ lọ si ẹgbẹlẹ́ òṣèlú All Progresses Congress…
Igbákejì Adarí ilé pè fún àtìlẹyìn Gúsù ilà oòrùn fún àtúnyàn Ààrẹ Tinubu
Igbákejì Adarí ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú, Ọ̀gbẹ́ni Benjamin Kalu, ti sọ pé sáà kejì tọ́ sí Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí a bá wo àwọn àṣeyọrí tí ó ti ṣe lórí àtúnṣe pàtàkì lórí ọrọ̀ ajé, àjọṣepọ̀ ará ìlú àti…
Abia 2027: Àwọn Adarí agbègbè rọ igbákejì adarí ilé láti díje Gómìnà
Àwọn agbaagba Ukwa-Ngwa ní gbègbè Aba ìgbà kan rí ní ìpínlẹ̀ Abia Abia ti bẹ igbákejì adarí ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin, Ọlọla Benjamin Okezie Kalu, láti díje fún ipò Gómínà nínú ìbò gbogbogbòò ọdún 2027.
Awọn…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Búra Fún Àwọn Olùbádámọ̀ràn, Ìgbìmọ̀ Ìjọba
Gómìnà Ìpínlẹ Kwara, AbdulRahaman AbdulRasaq ti búrafún olùbádámọ̀ràn méjì, aláyẹ̀wò àgbà tuntun fún akoto ìjọba àti àwọn akọ̀wé àgbà méje míràn
Lára wọn ni Alhaji Abdulrazaq Jiddah…
Ezigbo Gbé Pẹ́rẹ́gi Ìjà Kaná Pẹ̀lú Ẹgbẹ́ APC Ní Ìpínlẹ̀ Anambra
Ọ̀gbẹ́ni Valentine Ozigbo tí ó jẹ́ olùdíje nínú ìdìbò abẹ́le ẹgbẹ́ òsèlú APC fún ìgbáradì láti kópa nínú ìdíje sí ipò Gómìnà ní Ìpínlẹ̀ Anambra ti gbé ẹgbẹ́ òsèlú APC lọ sí ilé ẹjọ́ gíga ní ìlú Awka…
Àjọ IPCR Se Àtìlẹyìn Fún Ààrẹ Tinubu Látàrí Kíkéde Ìjọba Pàjáwìrì Ní Ìpínlẹ̀…
Àjọ tí ó wà fún àlàáfíà àti ìsàtúnṣe aáwọ̀, IPCR, ti lu Ààrẹ Tinubu lọ́gọ ẹnu látàrí kíkéde ìjọba pàjáwìrì ní Ìpínlẹ̀ Rivers, Orílẹ̀-èdè Naijiria
IPCR sàpèjúwe ìgbésẹ̀ Ààrẹ gẹ́gẹ́ bí èyí…
Ọmọ Asòfin Lu Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ebonyi Lọ́gọ Ẹnu Látàrí Gbígbé Ìgbésẹ̀ Akin Fún…
Ọmọ Ilé Asòfin tí ó ń sojú fún ẹkùn Afikpo/Edda ti ìpínlẹ̀ Ebonyi ní Ilé Asòfin Àpapọ̀ kejì, Iduma Igariwey, ti gbóríyìn fún Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ebonyi, Francis Nwifuru látàrí ìlàkàkà rẹ̀ èyí tí ó mú kí…