Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ

This is a category for politics news

Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀ Benue Pàṣẹ Títúléká Ní Àwọn Ìjọba Ìbílẹ̀- Agbẹnusọ…

Ìjọba ìpínlẹ̀ Benue ti sàlàyé pé títú àwọn ìjọba ìbílẹ̀ ká tí ó wáyé ní ìpínlẹ̀ Benue wà ní ìbámu pẹ̀lú òfin, lẹ́yìn àgbéyẹ̀wò tí ó wáyé láti ọwọ́ àwọn ọmọ Asofin Ìpínlẹ̀ náà   Sir Tersoo Kula,…

Ilé Ẹjọ́ Kòtẹ́milọ́rùn Fi Ìdí Ìjáwé Olúborí Kefas Múlẹ̀ Gẹ́gẹ́ Bí Gómìnà Tí Wọ́n…

Ilé Ẹjọ́ Kòtẹ́milọ́rùn tí ó wà ní ìlú Abuja ti fi ìdí ìjáwé olúborí Ọ̀mọ̀wé Kefas Agbu ti ẹgbẹ́ òsèlú PDP múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó jáwé olúborí nínú ìdìbo gómìnà tí ó wáyé ní ọjọ́ kejìdínlógún…

Gómìnà ìpínlẹ̀ Nasarawa Dẹ̀kun Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Láti Ta Àbùkù Bá Orúkọ Àwọn Adájọ Ni Ìpínlẹ̀ Náà.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Nasarawa ti dẹ́kun ẹgbẹ́ òṣèlú PDP láti má ṣe bú enu àbùkù Lu orúkọ àwọn adájọ ìpínlẹ̀ náà nitori eto ìdìbò to wáyé. Nínú ọ̀rọ̀ àtẹ̀jáde kàn tí Akọ̀wé àgbà fún Gómìnà ìpínlẹ̀ náà Abdullahi Sule sọ, Akọ̀wé fún ọ̀rọ̀ gbogbo,…
button