Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ

This is a category for politics news

Àjọ INEC Ìpínlẹ̀ Gombe Kéde Ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ̀n Osù Kẹrin Fún Ìdìbò Ìjọba Ìbílẹ̀

Àjọ Elétò Ìdìbò ti kéde ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n osù kẹrin ọdún 2024 gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ tí gómìnà ìpínlẹ̀ Gombe, Muhammadu Inuwa Yahaya fi ọwọ́ sí, fún síse ètò ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ náà   Nígbà tí…

Látàrí Ìdájọ́ Ilé Ẹjọ́ Gíga Lórí Awuye-wuye Tí Ó Wáyé Níbi Ìdíje Sí Ipò Gómìnà…

Kò dín ní ẹgbẹ̀rún ènìyàn tí ó jẹ́ alátìlẹyìn Kwankwasiyya ni ó péjọ ní ìjọba ìbílẹ̀ Keana, Ìpínlẹ̀ Nasarawa láti se àjọyọ̀ ìdájọ́ ilé ẹjọ́ àpapọ̀ èyi ́tí ó fi ìdí ìjáwé olúborí Abba kabir Yusuf múlẹ̀…
button