Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ

This is a category for politics news

Àwọn Gómìnà Lábẹ́ Ẹgbẹ́ Òsèlú PDP Sàgbékalẹ̀ Ọ̀bítí-bitì Owó Fún Àwọn Tí Ó Fi Ara…

Àwọn Gómìnà tí wọ́n Yànsípò Lábẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú PDP ti fi Ọgọ́rùn-ún Mílíọ̀nù náírà sé ìtọrẹ àánú fún àwọn tí ó fi ara káásá níbi ìkọlù tí ó wáyé ní Bokkos, Mangu, ní ìjọba ìbílẹ Barkin, ìpínlẹ̀…

Àdíkù Yóò Dé Bá Ìgbòkè-gbodò Ní Ìpínlẹ̀ Kano Látàrí Àtúndì Ìbò Tí Yóò…

Àjọ Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Kano ti sàlàyé pé àdíkù yóò bá lílọ-bíbọ̀ ní ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́fẹ́ẹ̀fà níbi tí ìrètí wà pé àtúndì ìbo yóò wáyé ní ìpínlẹ̀ náà   Kọmísọ́nà àjọ Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Kano,…

Àtúndì Ìbò Ìpínlẹ̀ Ebonyi – Mílíọ̀nù Mẹ́ta Ènìyàn Darapọ̀ Mọ́ Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC

Àtúndì Ìbò Ìpínlẹ̀ Ebonyi - Mílíọ̀nù Mẹ́ta Ènìyàn Darapọ̀ Mọ́ Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC Gomina ipinle Ebonyi, ọgbẹni Mr Francis Nwifuru ti fi ìdùnnú rẹ hàn latari bi awọn eniyan se tu jade ni yanturu lati ṣe atilẹyin fún ipolongo ibo fún ọmọ ẹgbẹ…

Àjọ INEC Yóò Pèsè Ẹgbẹ̀rún Mẹ́rin Òsìṣẹ́ Fún Àtúndì Ìbò Tí Yóò Wáyé Ní Ìpínlẹ̀…

Àjọ INEC ti fi ìgbáradì rẹ̀ hàn láti pèsè ẹgbẹ̀rún mẹ́rin òsìṣẹ́ fún àtúndì ìbò tí yóò wáyé ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọjọ́ kẹta osù kíní ọdún 2024, ní ìpínlẹ̀ kaduna   Alákòóso àjọ náà fún ìpínlẹ̀…
button