Browsing Category
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
This is a category for politics news
Olùdíje ilé aṣojú tẹ́lẹ̀, ìgbákejì adarí ilé fi PDP sílẹ̀ darapọ̀ mọ́ APC ní Kwara
Àwọn ògbóhùntarìgì ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party, PDP ní ìpínlẹ̀ Kwara, Abubakar Suka Baba àti Abubakar Musa pẹ̀lú ogunlọ́gọ̀ àwọn olólùfẹ́ wọn ti kéde ìdarapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ tí ń ṣèjọba, All Progressives Congress,…
Olùdíje Sí Ipò Gómìnà Méjì Nínú Ẹgbẹ́ Òsèlú APC Juwọ́ Sílẹ̀
Olùdíje sí ipò gómìnà méjì lábẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú APC ti fi ọwọ́ sílẹ̀ nínú ìdìbò tí ìrètí wà pé yóò wáyé ní ọjọ́ kọkànlá osù kẹsàn-án ọdún 2024
Igbákejì gómìnà tẹ́lẹ̀rí ní ìpínlẹ̀ Edo, Lucky…
Ìbò abẹ́lé APC Edo: APC ní kò rí bẹ́ẹ̀ o, ẹni tí kò láṣẹ láti kéde ìbò kò le kéde rẹ̀…
Ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress, APC, ti sọ pé irọ́ ni ò, ẹni tí kò láṣẹ láti kéde ìbò abẹ́lẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Edo, Gúsù Nàìjíríà tí ń lọ lọ́wọ́, kò kéde o.
Akọwe ipolongo lapapọ ti ẹgbẹ oṣelu All…
INEC fún ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣojú Taraba ní ìwé ẹ̀rí ìpadàbọ̀
Ìgbìmọ̀ olómìnira tí ń mójútó ètò ìdìbò lórílẹ̀-èdè (INEC), ti fún Tafida Abbas, tí ó jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣojú, ọmọ ọdún méjìlé-lọ́gbọ̀n ní ìwé ẹ̀rí ìpadàbọ̀ fún agbègbè ìjọba àpapọ̀…
Ize-Iyamu yọwọ́ nínú ìdíje gómìnà APC Edo
Ìkan lára àwọn olùdíje ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC), fún ìdìbò gómìnà ìpínlẹ̀ Edo ní ọjọ́ kọkànlé-lógún, oṣù kẹsàn án Àlùfáà Osagie Ize-Iyamu, ti jáwọ́ nínú ìdíje náà bí ìdìbò abẹ́lé…
Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Sokoto Búra Fún Ọmọ Ẹgbẹ́ Méjì
Ilé Ìgbìmọ̀ Asofin Sokoto ti búra fún ọmọ ẹgbẹ́ méjì ti wọn ṣẹṣẹ dibo fún ninu ibo atundi ti o waye ni ojo keta oṣù yii.
Abenugan ile igbimo asofin, Tukur Bala lo se ètò ibura yìí fún àwọn ọmọ ẹgbẹ tuntun ni Sokoto ni ọjọ…
Ìṣàkóso Ni Kókó Nínú Ètò Ìjoba Awarawa – Senetọ̀ Sunday Latung
Sénétọ̀ láti Àríwá orílẹ̀-èdè yii, Sénétọ̀ Sunday Latung láti Gusu Kaduna ti sọ pe ìṣàkóso rere ni o se pàtàkì nínú ètò ijoba àwarawa.
Ó sọ pé, ipinle Bayelsa àti gbogbo eniyan Ijaw nilo ìjoba rere bí eleyi ti gomina Douye Diri ti n se…
Ilé ìgbìmọ̀ Sokoto búra fún ọmọ ẹgbẹ́ tuntun méjì
Ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin Sokoto ti búra fún àwọn ọmọ egbẹ́ méjì tuntun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ dìbò yàn nínú àdìkù ìbò ọjọ́ kẹta, oṣù kejì ní agbègbè méjì ní ìpínlẹ̀ náà.
Adari ileigbimọ naa, Tukur Bala ni o ṣe ibura naa…
INEC ṣetán fun àdìkù ìbò Gúsù Enugu
Ìgbìmọ̀ Olómìnira tó ń ṣètò ìdìbò lórílẹ̀-èdè (INEC), ti sọ pé òhun ti ṣetán fún àdìkù ìbò agbègbè inú ìlú Gúsù Enugu tí wọ́n sún ọjọ́ rẹ̀ sí Ọjọ́ọ́rú, ọjọ́ kẹrìnlá, oṣù kejì.
Adari idanilekọ awọn…
Àdìkù Ìbò: Wọn búra fún Sẹ́nétọ́ tuntun mẹ́ta
Wọn ti bura fun Sẹnetọ mẹta ti o ṣẹṣẹ bori ninu ibo adiku ni awọn agbegbe wọn, ni ọjọ́ Iṣẹgun, ni inu ile igbimọ.
Awọn Sẹnetọ naa gba aṣẹ iwọle sinu ọfiisi niwaju aarẹ ile igbimọ, Godswill Akpabio, lasiko ijoko.
Awọn Sẹnetọ naa ni:…