Browsing Category
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
This is a category for politics news
Aya Gómìnà Se Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Obìnrin Ìpínlẹ̀ Anambra Láti Mú Ìgbòòrò Bá Ètò…
Aya Gómìnà Ìpínlẹ̀ Anambra, Arábìnrin Nonye Soludo ti se ìrànlọ́wọ́ fún àwọn obìnrin ọgbọ̀n lójúnà àti mú ìgbòòrò bá ètò ọrọ̀ ajé wọn nígbà tí ó ń se ìfilọ́lẹ̀ ètò kan tí ó wà fún ìdàgbàsóke àwọn…
Sẹ́nétọ̀ Kingibe Se Ìfilọ́lẹ̀ Àwọn Àkànṣe Iṣẹ Ní Ẹkùn Ti ́Ó Sojú Fún, Ó Jẹ́jẹ̀ẹ́ Láti…
Sẹ́nétọ̀ Ireti Kingibe jẹ́jẹ̀ẹ́ láti parí gbogbo àwọn iṣẹ́ tí ó dáwọ́lé ní olú ìlú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó jẹ́ ẹkùn tí ó sojú fún
Ó sọ ọ̀rọ̀ náà nígba tí ó ń sí òpópónà Karu-Ishan, ní…
Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Sokoto Gba Ìjọba Níyànjú Láti Jẹ́ Ki Oúnjẹ Pínpín Àkókò Ramadan Gbòòrò Si
Ile Ìgbìmọ̀ Aṣòfin ipinlẹ Sokoto ni ọjọ Ọjọ́rú gba àbádòfin kan wọle láti jẹ ki ounje pinpin Ramadan gbooro lọ sí ibilẹ mẹtalelogun yàtọ̀ si wipe ko duro gbari ni olu ìlú ipinle nikan.
Àbádòfin náà wa lati ọdọ Alhaji Bashar…
Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀ Nasarawa Buwọ́lu Ìyànsípò Ìgbìmọ̀ Fún Ọ̀rọ̀ Àkàndá Ẹ̀dá
Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀ Nasarawa buwọ́lu ìyànsípò Sale Barde-Keana gẹ́gẹ́ bí alága àti àwọn mẹ́rin míràn fún àmójútó ọ̀rọ̀ àwọn tí ó ní ìpèníjà ara ní ìpínlẹ̀ Nasarawa
Adarí Ile Ìgbìmọ̀ Asòfin…
látàrí Ìyànsípò Gómìnà Soludo Gẹ́gẹ́ Bí Olùbádámọ̀ràn Sí Ààrẹ Lórí Ètò Ọrọ̀…
Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀ Anambra, Somtochukwu Udeze ti gbósùbà fún Ààrẹ Tinubu látàrí ìyànsípò Gómìnà Chukwuma Soludo ti ìpínlẹ̀ Anambra gẹ́gẹ́ bí olùbádámọ̀ràn lórí ètò ọrọ̀ ajé
Ọ̀gbẹ́ni…
Àjọ ECOWAS Gbóríyìn Fún Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Senegal Fún Bíbọ̀wọ̀ Fún Òfin
Àjọ Economic Community of West African States (ECOWAS) ti gboriyin fún ààrẹ Orílẹ̀-èdè Senegal, Macky Sall, fún gbígba láti ju awà silẹ tí asiko rẹ lori aleefa bá ti pari bi ààrẹ gégé bí òfin se làá kalẹ̀.
Àjọ náà patewo fún…
Ìpínlẹ̀ Edo 2024: Akpata jáwé olúborí ní olùdíje ẹgbẹ́ Labour
Ààrẹ ẹgbẹ́ àwọn agbẹjọ́rò ní Nàìjíríà tẹ́l̀ẹ rí, NBA, Ọ̀gbẹ́ni Olumide Akpata ti jáwé olúborí nínú olùdíje ẹgbẹ́ Labour fún ìbò gómìnà àdìkù ní oṣù kẹsàn án 2024, ní ìpínlẹ̀ Edo.
Alaga igbimọ eto idibo…
Obi kò fi ẹgbẹ́ Labour sílẹ̀ o —Olùránlọ́wọ́
Olùránlọ́wọ́ fún ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ Peter Obi Media, POMR ti sọ pé ọ̀rọ̀ tí wọ́n ń sọ kiri pé ó fẹ́ fi ẹgbẹ́ Labour, LP, tí ó ti díje fún ààrẹ, ní 2023 sílẹ̀ kò rí bẹ́ẹ̀ o.
Olùránlọ́wọ́ fún ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀…
Ìbò abẹ́lé Gómìnà Edo: APC fi alága ìgbìmọ̀ ìdìbò míràn rọ́pò Uzodinma
Ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC ti fi elòmíràn rọ́pò Gómìnà ìpínlẹ̀ Imo, Hope Uzodinma bí alága ìgbìmọ̀ ìdìbò tí yóò ṣètò àtúndì ìbò abélé ẹgbẹ́ náà ní ìpínlẹ̀ Edo.
Eyi ni lati yanju…
Olùdíje ilé aṣojú tẹ́lẹ̀, ìgbákejì adarí ilé fi PDP sílẹ̀ darapọ̀ mọ́ APC ní Kwara
Àwọn ògbóhùntarìgì ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party, PDP ní ìpínlẹ̀ Kwara, Abubakar Suka Baba àti Abubakar Musa pẹ̀lú ogunlọ́gọ̀ àwọn olólùfẹ́ wọn ti kéde ìdarapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ tí ń ṣèjọba, All Progressives Congress,…