Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

Ó GBÓNÁ FẸLI-FẸLI

This is a category for LATEST NEWS

Ẹgbẹ́ ọmọ ilé àwọn tí kò pọ̀ bẹnu àtẹ́ lu Ìpànìyàn tó wáyé ní Ìpínlẹ̀ Edo

Ẹgbẹ́ ọmọ ilé Aṣojú ti àwọn tí kò pọ̀, ti bẹnu àtẹ́ lu bí ẹgbẹ́ oníjàgídíjàgan kan ní ìpínlẹ̀ Ẹdo ṣe ṣekú pa àwọn ọmọ Nàìjíríà tí kò dín ní mẹ́rìndín-lógún, tí àwọn ọmọ bíbí inú Arewa pọ̀jù lọ nínú wọn,…

Igbákejì Ààrẹ Shettima rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà láti gbé pọ̀ pẹ̀lú Ìṣọ̀kan àti…

Igbákejì Ààrẹ Kashim Shettima ti rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà láti gbé pọ̀ pẹ̀lú Ìṣọ̀kan Àlàáfíà àti ìfaradà gẹ́gẹ́ bíi òpo pàtàkii ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè, bí ẹ̀kọ́ tí ó wà nínú Ramadan. O sọrọ ni…

Quadri Aruna Ló Dára Jù Nílẹ̀ Adúláwọ̀ Nínú Eré Bọ́ọ̀lù Ẹlẹ́yin Orí Tábìlì

Quadri Aruna ti jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ẹlẹ́yin lórí tábìlì tó dára jùlọ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ báyìí, ó sún sí ipò kejìdínlógún lágbáyé. Ó ti síwájú ọmọ orílẹ̀-èdè Egípítì, Omar Assar láti jẹ́ ẹni tó dara jùlọ nínú bọ́ọ̀lù gbígbá ẹlẹ́yin lórí tábìlì tó…
button