Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ

This is a Nigeria news category

Ààrẹ Tinubu Ṣàfihàn Ìlọsíwájú Ẹgbẹ́ APC Sí Àwọn Àtúnṣe Ètò Ọrọ-àjé ‎

Ààrẹ Bola Tinubu tí sọ pé àtìlẹ́yìn tó ń pọ̀ sí i fún ẹgbẹ́ òṣèlú 'All Progressives Congress' (APC) ló jẹ́ àṣeyọrí àgbàyanu tí ẹgbẹ́ náà ṣe láàárín ọdún méjì àkọ́kọ́ tí wọ́n ti lò lẹ́nu iṣẹ́ ìjọba, ó sì fi dá àwọn ọmọ Nàìjíríà lójú pé…

Ètò Ẹ̀kọ́: Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Rẹmi Tinubu Bèrè Anfààní Ẹ̀kọ́ Ọfẹ Fún Àwọn Ọ̀dọ́.

Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Oluremi Tinubu, sọ wí pé oun ṣiṣe lórí bí ètò ẹ̀kọ́ ọfẹ yóò ṣẹ wa fun àwọn ọ̀dọ́ Nígbà tí o ń ba aláṣẹ ilé iṣé MERCK Foundation sọ̀rọ̀, ilé iṣé ti o jẹ aláàdáni láti Orílẹ̀-èdè German nígbà tí wọn ṣe àbẹ̀wò…

Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ní Ìlà Oòrùn Gúsù Ti Kìlọ Látàrí Ìpè Ìpàdé Àwọn Alẹ́nulọ́rọ̀ Tó Jẹ́ Òfegè

Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ní Ìlà Oòrùn Gúsù ti kìlọ fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀ láti má ka ìpè ipàdé pàjáwìrì àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ ní Abuja sí. Nínú àkọsílẹ̀ ìròyìn kan, alukoro ẹgbẹ́ ní ẹ̀ka ìlà oòrùn gusu, Chigozie Igwe, tẹnumọ…

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kéde Ìbẹ̀rẹ̀ Àjọ̀dún Eré Ìdárayá Orílẹ̀-èdè

Tí ìdùnnú tí ayọ̀ ní gbogbo àwọn ènìyàn wà nílùú Abeokuta, tó jẹ́ olu-ilu ìpínlẹ̀ Ogun, nígbà tí Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣe kéde ayẹyẹ eré ìdárayá ẹlẹ́ẹ̀kejìlélógún ní ìforígbárí, pẹ̀lú àwọn olóyè, àwọn olóṣèlú, àwọn ògbóǹtagí eré ìdárayá…
button