Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ

This is a Nigeria news category

FIFA Ṣàfihàn Orúkọ Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Tí Yóò Jẹ́ Olùdarí Eré Ìdárayá ti  2026

FIFA ti ṣe àkójọpọ̀ Orúkọ Àwọn Ọmọ Nàìjíríà tí yóò jẹ́ Olùdarí eré ìdárayá ní Àgbáyé ti ọdún 2026 ní gbángba, ó sì jẹ́rìí sí i pé àwọn ọgbọ̀n (30) ní a fọwọ́ sí láti dárí àwọn ìdíje àgbáyé ní onírúurú ẹ̀ka. ‎ ‎ Àkójọpọ̀ ọdọọdún náà ní…

Gómìnà AbdulRazaq Rọ Àwọn Aráàlú Láti Ṣ’àtìlẹ́yìn Fún-un Bí Ọdún 2026 Ṣé Bẹ̀rẹ̀

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara, Àárín Gbùngbùn Àríwá Nàìjíríà, AbdulRahman AbdulRazaq, ti ké sí àwọn aráàlú láti dúró ṣinṣin nínú àtìlẹ́yìn wọn fún ìṣàkóso rẹ̀ bí ọdún 2026 ṣé bẹ̀rẹ̀. ‎ ‎Ó ṣèlérí pé ìjọba yóò tẹ̀síwájú nínú ìsapá rẹ̀ láti mú…

Ìtọ́nisọ́nà Ṣé Pàtàkì Sí Ìgboyà Láti Darí Gẹ́gẹ́bí Aṣáájú Dáadáa – Mínísítà

Mínísítà fún Ìròyìn àti Ìtọ́sọ́nà Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mohammed Idris, ti tẹnu mọ́ ìmọ̀ràn àti ìtọ́sọ́nà gẹ́gẹ́ bí òun pàtàkì sí ìgboyà fún ẹnikẹ́ni láti darí bí aṣáájú réré. ‎ Mínísítà fún Ìròyìn sọ ọ̀rọ̀ yìí níbi ìpàdé kan tí…

Olóyè Pàtàkì Ni Ile Ẹjọ Gíga  Jùlọ Rọ Awon Adájọ Láti Se Ìdájọ Pèlú Àánú.

Olóyè Pàtàkì  ni ilé ẹjọ́ gíga jùlo ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Kabir Akanbi ti rọ àwọn adájọ kàkàkí Orílè-èdè Nàìjíríà láti ṣe ìdájọ pèlú Àánú lójú. Nígbà tí o ṣe Ẹgbẹ́ àwọn adájọ ti ìlú Abuja ( NAJUC) se ìbẹ̀wọ̀ sí Akanbi ni o ti rọ wọn…

Àwọn Òṣìṣẹ́ Elétò Aláàbò Dènà Àdó Olóró Láti Du Gbámú Ni Ìpínlẹ̀ Anambra.

Àwọn elétò òṣìṣẹ́ aláàbò nì ìpínlẹ̀ Anambra ti ba ìmọ̀ àwọn ènìyàn oníṣe laabi jẹ latari bi wọn ṣe dènà àdó olóró láti bí gbámú ni ìpínlẹ̀ náà  Lásìkò tí wọn ṣe àyẹwò sí ìbi ifarapamo àwọn ènìyàn oníṣe laabi náà tó wà ni ìjọba ìbílẹ̀…
button