Browsing Category
KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN
This is a category for featured story
Ecowas Pé Fún Ọwọ̀ Lórí Ìjọba Venezuela
Àwùjọ Ètò-ọrọ-àjé tí Àwọn Orílẹ̀-èdè Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà (ECOWAS) sọ pé àwọn wó idagbasoke túntún tí ń lọ́ ní Orílẹ̀-èdè Venezuela pẹ̀lú àníyàn nlá.
Gbólóhùn kan lati ọdọ Igbimọ ECOWAS sọ pe òun mọ́ pé ẹtọ wà láti kojú awọn òun…
Manchester United Tí Lé Olùkọ́ni Wọ́n Ruben Amorin
Manchester United ti lé olùkọ́ni Ruben Amorin kúrò nínú ikọ́ wọ́n, ẹgbẹ́ náà sọ ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kan lẹ́yìn tí wọ́n tá ọmi nínú ìdíje English Premiership.
Manchester United tí wà ní ipò kẹ́fà lórí akásọ ìdíje náà, tí wọ́n sì borí…
Cameroon Ṣéyà Fún South Africa Nínú Ìdíje AFCON
Cameroon borí South Africa pẹ̀lú àmì ayo 2–1 lati pèregede sí ìpele oníkọ̀ mẹ́jọ nínú ìdíje Ilẹ̀ Áfríkà (African Cup of Nations AFCON), ní ọjọ́ Àìkú ní Pápá Ìṣeré Al-Medina ní Rabat, Morocco.
South Africa bẹ̀rẹ̀ dáadáa nígbàtí…
Olùkọ́ni Sami Trabelsi Fí Tunisia Sílẹ̀ Lẹ́yìn Tó Pàdánù Nínú Ìdíje AFCON
Olùkọ́ni àgbà Tunisia Sami Trabelsi tí fí ipò rẹ̀ sílẹ̀ lẹ́yìn tí wọ́n yọ ẹgbẹ́ náà kúrò nínú ìdíje African Cup of Nations ní ìpele Round of 16, gẹ́gẹ́ bí àjọ bọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè náà ṣe fìdí rẹ̀ múlẹ̀.
Nínú ìròyìn kan lórí facebook, àjọ…
Gómìnà Seyi Makinde Kéde Ìṣípò-rọpò Nínú Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ Ìṣèjọba Rẹ̀, O Yan Akọ̀wé Ìjọba Tuntun.
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti kede Ọ̀jọ̀gbọ́n Musibau Adetunji Babatunde gẹ́gẹ́ bíi Akọ̀wé tuntun fún ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, lẹ́yìn tó yọ Ọ̀jọ̀gbọ́n Olanike Adeyemo tii ṣe akọ̀wé ìjọba tẹlẹ.
Eléyìí ló jẹyọ nínú àtẹ̀jáde láti ọwọ́…
Àwọn Ọmọ-ogun Ṣàfihàn Ẹní Tó Ń Ṣètò Ìpara-ẹni Láàrin Ìlú Ní Àríwá-Ìlà Oòrùn
Àwọn Ọmọ-ogun tó ń ṣiṣẹ́ ní Àríwá-Ìlà Oòrùn Nàìjíríà HADIN KAI (OPHK) tí fí Ọ́gbẹ́ni Shariff Umar hàn gẹ́gẹ́ bí ẹní tó ń ṣètò ìpara-ẹni láàrín ìlú pẹ̀lú ado olóró tó ṣẹ̀ṣẹ̀ wáyé, èyí tí àwọn Ológun náà tí gbìyànjú láti dúró.
Èyí ni…
Ààrẹ Tinubu Pàṣẹ Pé Kí Wọ́n Bẹ̀rẹ̀ Sí Máa Wá Àwọn Tó Ṣékọlù Kasuwan Daji
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí pàṣẹ fún Mínísítà fún ààbò, Olórí Àwọn Ológun, Àwọn Olórí Gbogbo Àwọn Ọmọ Ológun, Olórí Àwọn Ọlọ́pàá, àti Olùdarí Àgbà ti Ẹ̀ka Àwọn Iṣẹ́ Ìpínlẹ̀ (DSS) láti wá àwọn tó ṣe ìkọlù sí Kasuwan Daji kí wọ́n sì mú wọn ní…
Àwọn ọmọ ológun ti gba àwon ará ìlú tí wón jí gbé ní ìpínlẹ̀ Borno sílẹ̀
Àwọn ọmọ-ogun ti Operation HADIN KAI (OPHK) tún ti ṣe àṣeyọrí pàtàkì mììràn lẹ́nu iṣẹ́ wọn, nígbà tí wọ́n farabalẹ̀ kán lu àwọn oníjàgídíjàgan kan ní ìjọba ìbílẹ̀ Konduga, ti Ìpínlẹ̀ Borno, léèyí tí ó yọrí…
Gómìnà ìpínlẹ̀ Niger ṣèdárò àwọn afaragbà Borgu
Gómìnà ìpínlẹ̀ Niger, Àringbùngbùn Arewa Nàìjíríà, Mohammed Umaru Bago, ti banújẹ́ lórí ìkọlù àwọn oníjàgídíjàgan tí ó ṣẹlẹ̀ láìpẹ́ yìí ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Borgu, ti ìpínlẹ̀ náà, tí ó sì ń…
Ẹgbẹ́ ran àwọn tó ye ààrun jẹjerẹ ọyàn bọ́ lọ́wọ́ ni Anambra
Ẹgbẹ́ àwọn obìnrin ìpínlẹ̀ Anambra, ní Amẹ́ríkà Inc. àti Ẹgbẹ́ obìnrin ìpìnlẹ̀ Anambra ti Amẹ́ríkà tí ń rí sí Àjọṣepọ̀ lórí ààrùn jẹjẹrẹ ní Nàìjíríà, ti ṣàkójọ owó tó tó mílíọ́nù náìrà mẹ́ta láti ran…