Browsing Category
KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN
This is a category for featured story
Òjò tí ó lágbára kan gbẹ̀mí ènìyàn méje ní Mogadishu
Ó kéré jù, ènìyàn méje ti pàdánù ẹ̀mí wọn ní agbègbè méjì Mogadishu, nígbàtí ojó àgbàyanu kan rọ̀ tí ó sì fa omí yalé ní Ilà Oòrùn Áfíríkà ní ọjọ́ Ẹtì, gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ ìjọba kan ṣe sọ.
“A ti…
Bobi Wine ti Uganda yóò tún díje nínú ìdìbò Ààrẹ
Olórí ẹgbẹ́ alátakò Ugandan tí ó tún jẹ́ akọrin Bobi Wine ti kéde pé yóò tún díje nínú ìdìbò Ààrẹ ọdún 2026 tí ń bọ̀ yìí, léyìí tí yóò wáyé ní oṣù kìnníí.
Ẹni ọdun mẹtale-logoji ti orukọ rẹ gangan…
Ìpínlẹ̀ Nasarawa: Àjọ NAFDAC Tí Ilé Iṣé Omi Ti Ko Péye Tó.
Àjọ tó n mójú tó ọrọ oúnjẹ àti ògùn ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NAFDAC ) tí gbèsè le ilé iṣé olómi kan ni ìpínlẹ̀ Nasarawa léyìn ìgbà ti wọn kófìrí wí pé wọn Oka ojú òṣùwọ̀n to.
Ọ̀gbẹni Anga Emmanuel to jẹ igbákejì àjọ NAFDAC ló sọ èyí di…
Orílè-èdè Sierra Leone Ṣe Ìkìlọ Nlá Fún ilẹ Áfíríkà Nípa Àìsàn Mpox.
Látàrí àìsàn tí wọn n pé Mpox Orílẹ-èdè Sierra Leone ti ké sita fún àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Áfíríkà láti ni akiyesi nlá nítorí àìsàn náà gbilẹ báyìí.
Wọn ní kí àjọ eleto ìlera ni akiyesi pàtàkì kí àìsàn náà wà ba gbilẹ sí.
Dọ́kítà…
Ayẹyẹ ayajọ IDEOF: Irin Yóò Wáyé Ni Ìlú Abuja Àti Kaduna Láti Sààmì Sí Ayajọ Ọdún Náà.
Ẹgbẹ́ tí wọn pẹ ni (BFFWH) ti sọ wí pé ayẹyẹ ayajọ ọdún yii yóò dá lórí ìrìn láàrin Ìlú Abuja àti Kaduna.
Ibukun Ogundara tó jẹ agbẹnusọ fún ẹgbẹ́ náà ni o sọ èyí di mímọ̀ lásìkò to n ba àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ ni Kaduna, o ni kókó ìrin náà…
Irin Hajj 2025: Àwọn ìpele Àkọkọ Ti Gbéra Ló Sì Medinah.
Àwọn ìpele Àkọkọ fún ìrin àjọ Hajj 2025 ti wọn jẹ irínwó olè ni Ogun ti gbéra lọ sí Sáúdí Arábíà Fún iṣé ìrin àjọ Hajj.
Won gbéra kuro ni pápá kò òfurufú Sir Ahmadu Bello ni Birnin Kebbi, níbi ti Gómìnà ti ki wọn wí pé layo ni wón pada…
Gómìnà Borno Pàṣẹ Ki àwọn Ku Ọja Bama Ṣe.
Gómìnà ìpínlẹ̀ Borno Ọmowé Babagana Zulum ti pàṣẹ wí pé kí àtúnṣe àti ìyípadà de ba Ojà Bama èyí tó wà ni ìjọba ìbílẹ̀ Bama ni Maiduguri.
Kété ti Gómìnà ṣe ìbẹ̀wọ̀ sí ọjà náà ni o pa lasẹ wí pé kí wọn tún ọja náà ṣe sí ìgbàlódé.
Ó ní…
Ìpínlẹ̀ kano Buwọ́lù Lu Biliọnu Mẹta Fún Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Ti Yóò Ko Ìdánwò.
Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano ti ya owó Biliọnu Mẹta sọ tọ́ láti ṣe iranlọwọ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti yóò ko ìdánwò NECO ni ọdún yìí.
Ó ní èyí wa ni ìbámu pẹ̀lú èròngbà ìjọba ìpínlẹ̀ náà láti ṣe àtìlẹ́yìn fún ètò ẹ̀kọ́ àti ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn.…
Ààrẹ Tinubu ṣíṣọlójú ìgbìmọ̀ Ẹkùn, ṣàgbékalẹ̀ àwọn tó fà kalẹ̀ fún ilé ìgbìmọ̀…
Ààrẹ Bola Tinubu ti fún ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ní àkójọ àwọn orúkọ fún ìdásílẹ̀ ìgbìmọ̀ ìdàgbàsókè tuntun Árewá Àringbùngbùn, Gúsù oòrùn, àti Gúsù, tí ó sì ń bèèrè fún àyẹ̀wò àti ìfìdímúlẹ̀ wọn.…
Ẹ ṣàpọ́nlé ìṣẹ̀ǹbálẹ àwọn agbègbè tí ó gbà yín lálejò-Adarí gbogbogbòò…
Adarí gbogbogbòò fún àwọn Àgùnbánirọ̀ (NYSC), Ajagun Olakunle Nafiu, ti gba àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Àgùnbánirọ̀ nímọ̀ràn láti ṣàpọ́nlé ìṣẹ̀ǹbálẹ àwọn agbègbè tí ó gbà oníkúlukú wọ́n lálejò kí wọn ó sì jọ gbépọ̀…