Browsing Category
KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN
This is a category for featured story
Ó Lé Ní Ẹgbẹ̀rún Mẹ́talá Àwọn Oníjágìdíjagán Tí Á Tí Dá Lọ́wọ́ Kọ́ Láàrín Oṣù Kàrún 2023 Sí Ọdún Yìí…
Olùdámọ̀ràn Ààbò tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NSA), Mallam Nuhu Ribadu, tí sàlàyé pé ó lé díẹ̀ ní ẹgbẹ̀rún mẹ́talá àbọ̀ (13,543) àwọn oníjágìdíjagán àti àwọn afurasi ọdaràn mìíràn ní a tí dá lọwọ́ kọ́ yọ́ kúrò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti oṣù…
Ààrẹ Tinubu Ṣàfihàn Ìlọsíwájú Ẹgbẹ́ APC Sí Àwọn Àtúnṣe Ètò Ọrọ-àjé
Ààrẹ Bola Tinubu tí sọ pé àtìlẹ́yìn tó ń pọ̀ sí i fún ẹgbẹ́ òṣèlú 'All Progressives Congress' (APC) ló jẹ́ àṣeyọrí àgbàyanu tí ẹgbẹ́ náà ṣe láàárín ọdún méjì àkọ́kọ́ tí wọ́n ti lò lẹ́nu iṣẹ́ ìjọba, ó sì fi dá àwọn ọmọ Nàìjíríà lójú pé…
Ètò Ẹ̀kọ́: Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Rẹmi Tinubu Bèrè Anfààní Ẹ̀kọ́ Ọfẹ Fún Àwọn Ọ̀dọ́.
Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Oluremi Tinubu, sọ wí pé oun ṣiṣe lórí bí ètò ẹ̀kọ́ ọfẹ yóò ṣẹ wa fun àwọn ọ̀dọ́
Nígbà tí o ń ba aláṣẹ ilé iṣé MERCK Foundation sọ̀rọ̀, ilé iṣé ti o jẹ aláàdáni láti Orílẹ̀-èdè German nígbà tí wọn ṣe àbẹ̀wò…
Ìpínlẹ̀ Taraba Jé ilé Agbára Ṣugbọn Ko Sí Àtìlẹ́yìn.
Igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Kashim Shettima nínú ọ̀rọ̀ sọ wí pé ìpínlẹ̀ Taraba jẹ ilé agbára fún ohun ògbìn ṣugbọn konsi àtìlẹ́yìn fún.
Igbákejì Ààrẹ Shettima sọ èyí di mímọ lásìkò ajọdun ohun ògbìn ọdún 2025 to waye ni Jalingo.…
Ìpínlẹ̀ Ogun Yóò Fi Ẹwà Àṣà, Ìrìnajò-afẹ́ Rẹ Hàn Látàrí Àjọ̀dún Ìdíje Eré Ìdárayá
Ìpínlẹ̀ Ogun ti sọ pé àwọn yóò fi ẹwà Àṣà, Ìrìnajo-afẹ́ wọn hàn fáráyé látàrí àjọ̀dun Ìdíje eré ìdárayá Ẹlẹ́ẹ̀kejìlélógún National Sports Festival (NSF), tí wọ́n pè ní "Gateway Games" to ń lọ lọ́wọ́ ní ìlú Abeokuta.
Ọ̀gbẹ́ni Dare…
Orílẹ̀-èdè Algeria Yóò Rí Bílíọ̀nù Mẹ́ta Dọ́là Owó Ẹ̀yá Gbà Láti Ọ̀dọ̀ Báǹkì Ìdàgbàsókè Ìsìláàmù
Ààrẹ Banki Idagbasoke Isilaamu - "Islamic Development Bank" Muhammad Sulaiman Al Jass ti sọ pé Orílè-èdè Algeria yoo ri Biliọnu Mẹta Owó dọ́là ya laarin odun mẹta tẹ̀léra lati fi ṣe àwọn àkànṣe iṣẹ ìdàgbàsókè.
Ààrẹ…
Ọ̀jọ̀gbọ́n Soyinka Polongo Gbígbé Èdè Àbínibí Ilẹ̀ Wa Lárugẹ
Ọ̀jọ̀gbọ́n Wole Soyinka-"Nobel Laureate", ti tẹnumọ bó ṣe se pàtàkì láti gbé èdè abínibí ilẹ̀ wá àti àṣà òjogúnbá lárugẹ, wípé ó jẹ́ ohun ìwúlò pàtàkì fún ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè .
Ó sọ èyí ní ọjọ́ Ajé níbi ti o ti ń dáhùn ìbéèrè láti ọdọ…
Ipinlẹ Anambra Gbé Ìgbésẹ Akínkanjú Nípa Títún Àyíká Àti Bèbè Omi Ṣe.
Ìjọba ìpínlẹ̀ Anambra pẹ̀lú àjọsọpọ̀ - "Initiative for Agulu Development" ní ọnà láti ṣe ìmọ́tótó sì àwọn agbègbè ti omi wà àti àwọn àyíká rẹ àti ni ọ̀nà láti jẹ́ kí ẹ̀gbin omi dínkù, wọn ti ṣètò ìmọ́tótó ní gbogbo bèbè omi àti…
Wọ́n Fi Ìbò Gbé Ààrẹ NFF Wọlé Gẹgẹ Bí Ààrẹ WAFU B
Alága àjọ Nigeria Premier Football League (NPFL), Otunba Gbenga Elegbeleye ti gbósùbà fún idibo ààrẹ àjọ Nigeria Football Federation (NFF) Alhaji Ibrahim Gusau sì ipò alàkóso CAF West Africa Football Union(WAFU) B. bi èyí to dára àti…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara Ri Asia Iṣọkan
Àárín gbùngbùn ipinlẹ Kwara ti ri ásíà iṣọkan oní àádọ̀rin Mítà ní gíga ti gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq pé ìtúmọ̀ rẹ̀ ní "Iṣọkan àpapọ̀" - “national unity", àjọsọpọ Irinajo wà àti èròngbà wà gẹ́gẹ́ bí ènìyàn.
Ní ibi…