Browsing Category
ÌRÒYÌN YÀJÓ-YÀJÓ
This is a category for TRENDING NOW
Ààrẹ Tinubu kí Jim Ovia kú oríire ṣíṣàtẹ́wọ́gbà rẹ̀ sí Ìjọlá ìlú London
Ààrẹ Bọla Tinubu ti kí Jim Ovia, olùdásílẹ̀ tí ó tún jẹ́ Alága ilé ìfowópamọ́ Zenith, kú oríire ṣíṣàtẹ́wọ́gbà rẹ̀ sí Ìjọlá ìlú London.
Ninu Atẹjade kan lati ọdọ agbẹnusọ Aarẹ, Ọgbẹni Bayo Onanuga, Aarẹ…
Ẹgbẹ́ ọmọ ilé àwọn tí kò pọ̀ bẹnu àtẹ́ lu Ìpànìyàn tó wáyé ní Ìpínlẹ̀ Edo
Ẹgbẹ́ ọmọ ilé Aṣojú ti àwọn tí kò pọ̀, ti bẹnu àtẹ́ lu bí ẹgbẹ́ oníjàgídíjàgan kan ní ìpínlẹ̀ Ẹdo ṣe ṣekú pa àwọn ọmọ Nàìjíríà tí kò dín ní mẹ́rìndín-lógún, tí àwọn ọmọ bíbí inú Arewa pọ̀jù lọ nínú wọn,…
Igbákejì Ààrẹ Shettima rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà láti gbé pọ̀ pẹ̀lú Ìṣọ̀kan àti…
Igbákejì Ààrẹ Kashim Shettima ti rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà láti gbé pọ̀ pẹ̀lú Ìṣọ̀kan Àlàáfíà àti ìfaradà gẹ́gẹ́ bíi òpo pàtàkii ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè, bí ẹ̀kọ́ tí ó wà nínú Ramadan.
O sọrọ ni…
Makinde Kẹ́dùn Pẹ̀lú Ìdílé Ajimobi Àti Ìdílé Kola-Daisi
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde kẹ́dùn pẹ̀lú Abílékọ Florence Ajimobi tíì ṣe ìyàwó Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀ rí, olóògbé Abiola Ajimobi lórí ikú àkọ́bí ọmọ rẹ̀, Bisola Kola-Daisi.
Gẹ́gẹ́ bí àtẹ̀jáde ti Akọwe Ìròyìn fún Gómìnà,…
Ilé Asòfin Se Àtìlẹyìn Fún Ìgbésẹ̀ Ààrẹ Látàrí Ìkéde Ìjọba Pàjáwìrì Ní…
Ilé ìgbìmọ̀ Asòfin kejì ti buwọ́lu ìgbésẹ̀ Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu pẹ̀lú ìkéde ìjọba pàjáwìrì tí ó wáyé ní ìpínlẹ̀ Rivers
Wọ́n se àtìlẹyìn fún ìgbésẹ̀ náà lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n gba ìwé àtẹ̀jísẹ́…
Mínísítà rọ àwọn akọ̀ròyìn lórí ìròyìn déédé àti ọ̀rọ̀ ọlọgbọ́n
Ilé iṣẹ́ Nàìjíríà tí ń mójútó ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìpele kejì ìbáraenisọ̀rọ̀ ilé iṣé náà fún ọdún 2025, tí ó sì rọ àwọn akọ̀ròyìn láti fi ìròyìn déédé, ìwọ̀ntún wọ̀nsì, àti ìsòdodo…
VON, NADDC yóò fọwọ́sowọ́pọ̀ láti ṣàgbélárugẹ abala ọkọ̀ Ayọ́kẹ́lẹ́
Ilé Akéde Nàìjíríà (VON) àti ilé iṣẹ́ tí ń rí sí Ìyàwòrán àti Ìdàgbàsókè ọkọ̀ Ayọ́kẹ́lẹ́ lórílẹ̀-èdè (NADDC), ń fọwọ́sowọ́pọ̀ láti ṣe àgbélárugẹ ìdàgbàsókè abala ọkọ́ Ayọ́kẹ́lẹ́ Nàìjíríà.
Lasiko…
Arábìnrin Àkọ́kọ́ Nàìjíríà yóò ró àwọn obìnrin tó lé ní ẹgbẹ̀rún méjìdín-lógún…
Lórí ṣíṣa ipá rẹ̀ láti ró àwọn obìnrin lágbára fún ọrọ́ ajé àti ìdàgbàsókè àtile dá dúró, pàápàá jul̀ọ ní àwọn ìgbèríko, Arábìnrin Àkọ́kọ́ Nàìjíríà, Oluremi Tinubu, ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ ètò…
Ètò Ìdásí: Ìjọba Nàìjíríà yóò ran àwọn àgbẹ̀ lọ́wọ́
Nínú akitiyan láti kojú làásìgbò àìróńjẹ tótó, Igbákejì ààrẹ Kashim Shettima ti túnbọ̀ fi ìdí ìpinnu ìjọba Nàìjíríà múlẹ̀ lórí ṣíṣàtìlẹyìn fún àwọn àgbẹ̀ nípasẹ̀ àwọn ètò àfojúsùn ìdásí.…
Sẹ́nétọ̀ Nwebonyi fún àwọn aláìní ní ẹ̀bùn ilé ní ìpínlẹ̀ Ebonyi
Igbákejì ọ̀gá àgbà whip ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú ti Nàìjíríà, Sẹnetọ Onyekachi Nwebonyi ti ṣe àgbékalẹ̀ ilégbèé aládàákọ́ méjì, oní yàrá méjì àti kànga ìgbàlódé sí agbègbè rẹ̀.
Iyawo Gomina ipinlẹ Ebonyi,…