Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN YÀJÓ-YÀJÓ

This is a category for TRENDING NOW

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Tẹ́lẹ̀ rí, Ọmọlolu Olunlọyọ Jáde Láyé

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti fi ikú ẹni tó ti fi ìgbà kan rí jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ọ̀mọ̀wé Victor Ọmọlolu Olunlọyọ wé àdánù nlá Makinde lo sọ ọ̀rọ̀ yìí nínù àtẹ̀jáde kan eléyìí to fi kẹ́dùn pẹ̀lú ìdílé Olunlọyọ, gbogbo ọmọ…

Ìyàwó Gómìnà Èkó pè fún Àlàáfíà, Ìṣètọrẹ ànúú bí oṣù Ààwẹ̀ ṣe parí

Ìyàwó Gómìnà Èkó, Dokita Claudiana Ibijoke Sanwo-Olu ti rọ àwọn ará ìlú láti jẹ́kí ẹ̀mí  Àlàáfíà, Ìṣètọrẹ ànúú, àti Ìṣọ̀kan máa báwọn gbé, bí oṣù Ààwẹ̀ ṣe parí. Nigba ti o n ba awọn Musulumi sọrọ ni…
button