Browsing Category
ÌRÒYÌN YÀJÓ-YÀJÓ
This is a category for TRENDING NOW
Emir ti ìlú Ìlorin gbàdúrà fún Nàìjíríà, Ààrẹ, Gómìnà Kwara
Emir ti ìlú Ìlorin tí ó tún jẹ́ Alága ìgbìmọ̀ lọ́balọ́ba ní ìpínlẹ̀ Kwara, Arewa Àringbùngbùn Nàìjíríà, Alhaji Ibrahim Sulu-Gambari ti pe ìṣàdúrà pàtàkì fún àlàáfíà àti ìdúróṣinṣin orílẹ̀-èdè, ní…
Ilé ìwòsàn Ìkọ́ni pàtàkì ìwà láláàfíà àwọn òṣìṣẹ́ – CMD
Ọ̀gá Àgba Adarí Ìṣòògùn, CMD, ti gbọ̀ngàn ilé ìwòsàn Ìkọ́ni ti ilé Ẹ̀kọ́ Gí́ga Fáfítì Ọbafemi Awolọwọ , OAUTHC, Ilé-Ifẹ̀, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun , Gúsù- Ilà Oòrùn, Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n John Okeniyi ti ṣàlàyé pé…
Òjò tí ó lágbára kan gbẹ̀mí ènìyàn méje ní Mogadishu
Ó kéré jù, ènìyàn méje ti pàdánù ẹ̀mí wọn ní agbègbè méjì Mogadishu, nígbàtí ojó àgbàyanu kan rọ̀ tí ó sì fa omí yalé ní Ilà Oòrùn Áfíríkà ní ọjọ́ Ẹtì, gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ ìjọba kan ṣe sọ.
“A ti…
Bobi Wine ti Uganda yóò tún díje nínú ìdìbò Ààrẹ
Olórí ẹgbẹ́ alátakò Ugandan tí ó tún jẹ́ akọrin Bobi Wine ti kéde pé yóò tún díje nínú ìdìbò Ààrẹ ọdún 2026 tí ń bọ̀ yìí, léyìí tí yóò wáyé ní oṣù kìnníí.
Ẹni ọdun mẹtale-logoji ti orukọ rẹ gangan…
Ààrẹ Tinubu ṣíṣọlójú ìgbìmọ̀ Ẹkùn, ṣàgbékalẹ̀ àwọn tó fà kalẹ̀ fún ilé ìgbìmọ̀…
Ààrẹ Bola Tinubu ti fún ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ní àkójọ àwọn orúkọ fún ìdásílẹ̀ ìgbìmọ̀ ìdàgbàsókè tuntun Árewá Àringbùngbùn, Gúsù oòrùn, àti Gúsù, tí ó sì ń bèèrè fún àyẹ̀wò àti ìfìdímúlẹ̀ wọn.…
Ẹ ṣàpọ́nlé ìṣẹ̀ǹbálẹ àwọn agbègbè tí ó gbà yín lálejò-Adarí gbogbogbòò…
Adarí gbogbogbòò fún àwọn Àgùnbánirọ̀ (NYSC), Ajagun Olakunle Nafiu, ti gba àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Àgùnbánirọ̀ nímọ̀ràn láti ṣàpọ́nlé ìṣẹ̀ǹbálẹ àwọn agbègbè tí ó gbà oníkúlukú wọ́n lálejò kí wọn ó sì jọ gbépọ̀…
TIME100 Ṣèdánimọ̀ àwọn adarí Nàìjíríà méjì kan nínú ètò ìlera Àgbáyé
TIME 100 Ìlera ti ọdún 2025 ti dá orúkọ Mínísítà fún ètò ìlera àti ìwà lálàáfíà Àwùjọ, Ọ̀jọ̀gbọ́n Muhammad Ali Pate, àti Adarí fún ètò ohun jíjẹ, Ìyáàfin Ladidi Bako-Aiyegbusi.
Igbakeji Adari, eto…
Hajj 2025: Igbákejì Ààrẹ Shettima ṣe ìfilọ́lẹ̀ ọkọ̀ òfurufú alákọ̀ọ́kọ́ àwọn arìnrìn…
Igbákejì ààrẹ Kashim Shettima, ṣe ìfilọ́lẹ̀ ọkọ̀ òfurufú àwọn arìnrìn àjò Nàìjíríà alákọ̀ọ́kọ́ ti ọdún 2025, ní ọjọ́ Ẹtì ní pápákọ̀ òfurufú tí ń kẹ́rù, ti Owerri, ní ìpínlẹ̀ Imo.
Ayẹyẹ yii ṣami igbera…
Ìgbìmọ̀ Aláṣe Àpapọ̀ FEC buwọ́lu ìwé òfin tí yóò dá ìgbìmọ̀ tí ń rísí Ìṣàkóso…
Ìgbìmọ̀ Aláṣe Àpapọ̀ (FEC), tí Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu jẹ́ alága rẹ̀ ti buwọ́lu ìwé òfin tí yóò dá ìgbìmọ̀ tí ń rísí Ìṣàkóso Kòkóó (NCMB), sílẹ̀ tí èyí sì jẹ́ ìgbésẹ̀ pàtàkì láti ṣàgbéǹde ilé iṣẹ́…
Makinde Mú Ayípadà Rańpe Dé Bá Ipò Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ Rẹ̀
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti mú ayípadà ránpẹ́ dé bá ipò àwọn ìgbìmọ̀ aláṣẹ nínú ìṣèjọba rẹ̀.
Gẹ́gẹ́ bí ìwé tí olórí àwọn òṣìṣẹ́ Gómìnà, Ṣẹgun Ogunwuyi fi síta ni ọjọ́ Ajé, (05/05/3025) ṣe fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé, Komisana fún Ohun…