Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌLERA
This is a category for health news
Àìsàn Lassa: Àjọ NCDC So Wí Pé Ènìyàn Ọgọrin Ti Jáde Láyé Ni Ìpínlẹ̀ Mọkanla.
Àjọ tó n mójú tó ọrọ ìlera ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà NCDC tí fi tó àwọn ènìyàn létí wí pé àwọn ọgọrin ènìyàn ló ti jade láyé ní ìpínlẹ̀ mọ́kaànlá látàrí àìsàn iba Lassa.
Ìròyìn yìí di mímọ̀ láti ori èrò ayélujára láti ọdọ àjọ NCDC.
Wọ́n…
Àjọ NAFDAC Sèkìlọ̀ Fún Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Láti Jìnà Sí Ọtí Àmupara
Àjọ NAFDAC ti sèkìlọ̀ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ nípa ewu tí ó wà níbi ọtí àmujù àti lílo òògùn ní ìlòkulò
Ọ̀jọ̀gbọ́n Mojisọla Adeyẹye tí ó jẹ́ alákòsóo àjọ náà ni ó sèkìlọ̀ níbi ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kan ti o…
Naìjírìà Ṣàfihàn Ètò Oúnjẹ Àṣárá Lóore ‘N774’
Ìjọba Nàìjíríà tí ṣé ìfilọ́lẹ̀ ètò ìjẹ́ẹmú tí orílẹ̀-èdè tí á npè ní 'Nutrition 774' oúnjẹ àṣárá lóore
Ètò ìjẹ́ẹmú náà ní yóó kán gbogbo àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ẹẹdẹgbẹrinlelaadọrinatimẹrin (774) ní Nàìjíríà láti mú ìrọ̀rùn bá…
Ìtọ́jú Agbègbè: Adari ilé iṣé ìjọba Fún Ìtọ́jú Agbègbè Gbóríyìn Fún Ìjọba.
Adarí àgbà fún ilẹ isé itọju agbègbè,Iyaafin Dídì Esther Walson-Jack tí gbé Oriyin fún ìjọba àpapọ fún atilẹyin wọn nípa bí agbègbè yóò ṣe wá ni ìlera tó péye fún àwọn ènìyàn.
Ó gbé osuba o Kare fún ìjọba bí wọn ṣe fi ìlera àti ìtọjú…
Ijóba Ipinlẹ Kwara Múra Sí Ìgbógun Ti Ìgbọ̀nsẹ̀ Ṣíṣe Ní Ìta Gbangba
Ijóba Ìpínlẹ̀ Kwara ti fi dá àwọn ènìyàn rẹ̀ lójú pé òun yoo se ise òun bí iṣẹ́ nípa líla àwọn ènìyàn lọ́yẹ̀ ewu tó wà ninú ki àwọn kan máa se ìgbọ̀nsẹ̀ síta gbangba káàkiri.
Nígbàtí ó ń bá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀, ọ̀gá àgbà Ilé iṣẹ Kwara…
Àjọ NLC Pàrọwà Sí Ìjọba, Ìjọ Ẹlẹ́sìn Gbogbo Láti Mú Ìgbòòrò Bá Ètò Ìlera
Ààrẹ Ẹgbẹ́ Òsìṣẹ́, Ọ̀gbẹ́ni Joe Ajero ti pàrọwà sí ìjọba àti àwọn ẹlẹ́sìn gbogbo láti gbé ìgbésẹ̀ èyí tí yóò mú ìdàgbàsókè bá ètò ìlera ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Ajero sọ ọ̀rọ̀ náà nígbà…
Dalori Gbosuba Ràbàndẹ̀ Fún Ìdàgbàsókè NAUTH Nígbà Tí Ó Se Àbẹ̀wò
Alága tuntun asẹ̀sẹ̀yàn ti Ifáfitì ẹ̀kọ́sẹ́mọsẹ́ - Nnamdi Azikiwe University Teaching Hospital (NAUTH) ní ìlú Nnewi, ìpínlẹ̀ Anambra, Alhaji Ali Bukar Dalori ni ọjọ́ Ẹtì bẹ̀rẹ̀ àbẹ̀wò sí ohun èèlò ilé ìwòsàn láti se àyẹwò sí…
Àmójútó Tí Ó Péye Wà Fún Ẹka Ètò Ìlera- Ọ̀jọ̀gbọ́n Pate Síṣọ Lójú Ọ̀rọ̀
Mínísítà Ètò Ìlera àti Àlàáfíà Ọmọnìyàn, Ọ̀jọ̀gbọ̀n Muhammed Ali Pate ti sàlàyé ipa ribiribi ti ìjọba ńkó lahti rí i dájú pe ètò ìlera tí ó yanjú wà fún ọmọ Naijiria
Ó sọ ọ̀rọ̀ náà nígbà tí…
Ààrẹ Tinubu Buwọ́lu Gbígba Àwọn Akọ́ṣẹ́mọsẹ́ Elétò Ìlera Láti Sàmójútó Ọgbà Ìsàtúnṣe…
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bọla Ahmed Tinubu ti buwọ́lu ìgbanisíṣẹ́ àwọn dókítà akọ́ṣẹ́mosẹ́ elétò ìlera àádọ́ta àti àwọn olùrànlọ́wọ́ wọn tí ó tó ọgọ́rùn-un fún àmójútó ètò ìlera àwọn tí ó wà nínú…
Àwọn Adarí Ẹlẹ́sìn Kristeni Parapò Láti Dènà Ìwà ìbàjẹ́ Láwùjọ
Pàtàkì Ìdánilékòó ọlọ́jwọ́ márùn-ún fún àwọn adarí ẹṣin Kristẹni ni láti dènà ìwà ìbàjẹ́ láàrin àwọn ènìyàn láwùjọ.
Ilé iṣé LuxTerra Leadership Foundation ló mú kí àwọn asíwájú Kirisiteni mẹta lẹ lógbón parapò fún ètò náà
Wọn ní…