Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌLERA
This is a category for health news
Alága Ìjọba Ìbílẹ̀ Se Ìfilọ́lẹ̀ Àtúnṣe Ilé Ìwòsàn Alábódé Ní Ìlú Omu-Aran
Alága ìjọba Ìbílẹ̀ Ìfẹ́lódùn, Ìpínlẹ̀ Kwara, Ọ̀gbẹ́ni Abdulazeez Yakubu ti se ìfilọ́lẹ̀ ní Ọjọ́rú láti se àtúnṣe ilé ìwòsàn alábọ́dé tí ó wà ní Ofe Aran, ní Ilu Omu-Aran
Nígbà tí ó ń sọ̀rọ̀,…
Ìgbáyégbádùn Àwọn Dókítà Onímọ̀ Ìsègùn Òyìnbó Se Pàtàkì- Ẹgbẹ́ Dókítà Ẹka Ti…
Ẹgbẹ́ Àwọn Dókítà Onímọ̀-Ìsègùn Òyìnbó ẹka ti Abuja ti pàrọwà sí ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin láti bu ojú àánú wo ọ̀rọ̀ ìgbáyégbádùn àwọn ọmọ ẹgbẹ́ náà
Dókítà Emeka Ayogu tí ó jẹ́ alága ẹgbẹ́ náà ní ẹka…
Ìjọba Àpapọ̀ Buwólu Òbítíbitì Owó Fún Ìdàgbàsókè Ètò Ìlera Ní Orílẹ̀-èdè…
Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti gbé iṣẹ́ fún àwọn agbáṣẹse tí yóò pèsè ohun èlò ìlera pẹ̀lú bíbuwọ́lu bílíọ̀nù mẹ́wàá lé ọwọ́ mẹ́ta láti fi ra àwọn ohun èlò náà
Nígbà tí ó ń ba àwọn akọ̀ròyìn…
Òmìnira Àwọn Aláìsàn Se Pàtàkì Ní Ilé Ìwòsàn Gbogbo- Àjọ Kan Ti kì í Se Ti Ìjọba…
Àjọ Disney Foundation ti pàrọwà ní ọjọ́ Àbámẹ́ta sí ọmọ Naijiria láti sàfihàn títẹ ẹ̀tọ́ wọn lójú mọ́lẹ̀ nígbà tí wọ́n bá wà ní ilé ìwòsàn fún ìtọ́jú
Ọ̀gbẹ́ni Martins Nwanne pe ìpé náà níbi ayẹyẹ…
Ni Ìpínlẹ̀ Oyo Ṣe Ìtọ́jú Ọfẹ Fún Àwọn Ọmọ Ilé Ìwé Alakobere.
Bí ètò ìtọjú ìlera ṣe di ohun inira fún ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà báyìí pàápàá jùlọ àwọn ọmọdé, Ìpínlẹ̀ Oyo ti ṣe Ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ọmọdé nípa ètò ìtọ́jú ìlera ọfẹ.
Àjọ àgbáyé fún ètò ìlera sọ wí pé òpòlopò àwọn ènìyàn,…
Àjọ UNFPA Gbé Àwọn Ohun Èlò Ètò Ìfẹ̀tọ̀sọ́mọíbí Fún Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kano.
Àjọ tí wọn pẹ ni United Nations Population Fún (UNFPA) ni ọjọ̀bọ̀ ti fá àwọn ohun èlò fún ètò Ifetosomobibi fún ìjọba ìpínlẹ̀ Kano.
Dọ́kítà Audu Alayande, tó jẹ aṣojú fún Àjọ náà sọ wí pé oun mú àwọn elo náà wà fún lílò àti àlàáfíà àwọn…
Ẹgbẹ́ Àwọn Oníṣègùn Nípa Ẹyìn Àti Ìlera Ṣe Ayẹyẹ Fún Àwọn Oníṣègùn Òyìnbó Mẹ́ẹ̀dógún Ni Fásítì…
Ẹgbẹ́ Oníṣègùn àti ìtójú ẹyìn ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (MDCN) ni ọjọ̀bọ̀ ṣe ayẹyẹ fún àwọn Oníṣègùn òyìnbó tuntun mẹẹdogun tí wọn kose Mósè ní Fásítì Igbinedion.
Eléyìí jẹ ayẹyẹ Eleekeji iru rẹ tí yi yóò wáyé, ni ile ẹ̀kọ́ gíga náà alakọkọ…
NAFDAC Ṣèlérí Látí Ṣé Àbójútó Òògùn Ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Àjọ tí orílẹ̀-èdè fún Oúnjẹ àti Oògùn fún àbójútó àti ìṣàkóso (NAFDAC) sọ pé àwọn kó ní sinmi lórí ìṣẹ́ rẹ̀, nínú ìgbìyànjú rẹ̀ láti ṣàkóso lílo òògùn ní Nàìjíríà
Olùdarí àgbà tí ilé-iṣẹ́ náà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Mojisola Adeyeye, ṣé ìkéde…
Agùnbánirọ̀ Pín Ohun Èèlò Àlejò Obìnrin Fún Àwọn Ọmọbinrin Ní Ìpínlẹ̀ Kogi
Agùnbánirọ̀ kan, ọmọ ẹgbẹ́ àti Olùdásílẹ̀ ètò 'Pet' ti orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Victoria Toluwaloju, ti pín ohun èèlò àlejò Obìnrin fún ọmọ ilé ìwé tó jẹ́ ẹgbẹ̀rún kan ó dín mẹ́tàlá kaakiri àṣàyàn ilé ẹkọ gíga márùn ún ìpínlẹ̀ Kogi fún…
Onímọ̀ Nípa Àìsàn ọpọlọ Bèrè Fún Atilẹyin Nípa Ìlera Ọpọlọ Láàrin Agbègbè.
Onímọ̀ nípa Àìsàn ọpọlọ Dọ́kítà Zubairu Umar ti rọ àwọn ènìyàn ni àgbègbè láti ni àkíyèsí àwọn ènìyàn nípa àìsàn ọpọlọ ni agbègbè fún ìtọ́jú lásìkò.
Umar to jẹ igbákejì ilé ìwòsan ìjọba àpapọ̀ to n mójú ètò ọpọlọ ni ìpínlẹ̀ Kware ni…