Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌLERA

This is a category for health news

Ẹgbẹ́ Bèrè Fún Ìrànlọ́wọ́ Ìjọba Fún Ìdàgbàsókè Àwọn Ilé ìwòsan Ní Ìpínlẹ̀ Kogi.

Ẹgbẹ́ àti àwọn tọrọ kàn ni àwọn ilé ìwòsan to pàtàkì ni ìpínlẹ̀ Kogi ti pé fún ìrànlọ́wọ́ ìjọba ìpínlẹ̀ Kogi láti ṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn ilé ìwòsan ìjọba ni ìpínlẹ̀ náà. Wọn rawọ́ ẹ̀bẹ̀ náà lásìkò tí wọn ṣe àbẹ̀wọ̀ sí Adarí àgbà pátápátá…

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Àti Ilé  Iṣé Aláàdáni Yóò Ni Ìbáṣepọ̀ Láti Mú Ìdàgbàsókè Ba Ilé Ìwòsàn…

Ìjọba àpapọ̀ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí buwolu ìwé ìbáṣepọ̀ láàrin ilé ìwòsan ìjọba National Hospital ti Abuja àti ilé ìwòsan aláàdáni merin míràn láti mú ìdàgbàsókè ba ètò ìlera Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Nígbà tí o n sọrọ níbi ayẹyẹ náà Mínísítà…

Àìsàn Inú Àti Ọ̀fun: Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ti Pàdánù Àwọn Ènìyàn Tó Lẹ Ni Ọgọrùn Látàrí Abẹ́rẹ́…

Àjọ tó n mójú tó ètò ìlera ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà NCDC, sọ wí pé àwọn ènìyàn tó lẹ́ ni ọgọrùn ni o ti pàdánù emi wọn látàrí àìsàn to n ba inú àti Ọ̀fun jà èyí to n ṣẹlẹ báyìí nì Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Àjọ NCDC sọ èyí di mímọ̀ nígbà tí wọn…
button