Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌLERA
This is a category for health news
Ìjàmbá Àdó Olóró Ni Ìpínlẹ̀ Kaduna: Ẹgbẹ́ NMA Pé Fún Ìrànlọ́wọ́ Sí Àwọn Tó Ṣẹlẹ̀ Sí.
Ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ ìlera tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ìpínlẹ̀ Kaduna pé fún ìrànlọ́wọ́ sí àwọn ènìyàn tí ìjàmbá àdó olóró náà ṣẹlẹ̀ sí ní Tudun Biri ni Ìpínlẹ̀ Kaduna.
Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí mú kí ọpọ àwọn ènìyàn pàdánù Èmí wọn ní ọjọ́ kẹrin oṣù Kejìlá…
Akọ̀wé gbogbogbòò rọ àwọn Dókítà, òṣìṣẹ́ elétò ilérà láti dúró sí Nàìjíríà
Akọ̀wé gbogbogbòò, Ilé iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tí ń mójútó ètò ààbò, Dókítà Ibrahim Abubakar Kana, ti ṣàlàyé pé ìjọba àpapọ̀ ń sa gbogbo ipá rẹ̀ láti ṣàtúnṣe lórí abala ètò ìlera ní Nàìjíríà, tí ó ṣì…
Àjọ Kan Tí Kì í Se Ti Ìjọba Fọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú Ìjọba Ìpínlẹ Ogun Láti Mú Ìdàgbàsókè…
Àjọ kan tí kì í se ti ìjọba (Interswitch) ti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ìjọba ìpínlẹ̀ Ogun lójúnà àti mú ìgbòòrò bá ètò ìlera ní ìpínlẹ̀ náà
Ọ̀gbẹ́ni Osasere Atohengbe tí ó jẹ́ igbákejì alága àjọ náà ni…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó Se Ìrànwọ́ Fún Ètò Ìlera
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Ọ̀gbẹ́ni Babajide Sanwo-Olu ti kéde ìpinnu ìsèjọba rẹ̀ láti se ìrànlọ́wọ́ fún ètò ìlera èyí tí yóò mú ìrọ̀rùn bá àwọn ènìyàn ìlú
Ó sàlàyé pé ìgbésẹ̀ náà wáyé láti mú…
Awọn Onímọ̀ Nípa Ọpọlọ Gbà Ìjọba Àpapọ̀ Làmọ̀ràn Láti Kọjú Àwọn Ohun Tí Ó Fa Ààrùn Ọpọlọ.
Onímọ̀ nípa Àrùn Ọpọlọ Dọ́kítà Jibril Abdul malik ti pé ìjọba àpapọ̀ láti ṣe àtúnṣe sí àwọn ohun tó leè fa àisàn ọpọlọ láwùjọ
Dọ́kítà Abdul malik ti ilé ìwòsàn ìjọba UCH Ibadan lo sọ èyí di mímọ̀ níbi ìpàdé àwọn Dọ́kítà nipa àìsàn Ọpọlọ…
Ìrọ̀rùn Wọ̀lú: Ìjọba Àpapọ̀ Buwọ́lu Gbígba Àwọn Dókítà Ìsègùn Òyìnbó Síṣẹ́ Ní…
Ìjọba àpapọ̀ ti buwọ́lu ìgbanisíṣẹ́ igba ènìyàn tí ó jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ dókítà onímọ̀ ìsègùn òyìnbó àti àwọn olùrànlọ́wọ́ oníṣẹ́ ètò ìlera ní ilé ìwòsàn ìjọba àpapọ̀ tí ó wà ní Idi-Aba, Abẹokuta,…
Ìgb́ayégbádùn Àwọn Òsìṣẹ́ Elétò Ìlera Se Pàtàkì- Ẹgbẹ́ Òsìṣẹ́ Elétò Ìlera Kan…
Ẹgbẹ́ Òsìṣẹ́ Elétò Ìlera kan ti pàrọwà sí ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó láti mú ìgbáyégbádùn àwọn òsìṣẹ́ elétò ìlera ní ọ̀kúkúdùn, wọ́n sàfikún pé dókítà onísègùn òyìnbó mẹ́ẹ̀dógún ni ó pàdànú ẹ̀mí…
Àjọ Alẹ́nulọ́rọ̀ Kan Pè Fún Fífi Òpin Sí Dídá Ẹyẹ Sí Àwọn Àkàndá Ẹ̀dá
Àjọ kan tí ó ń rí sí ọ̀rọ̀ àwọn àkàndá ẹ̀dá ti pè fún fífi òpin sí dídá ẹyẹ sí àwọn àkàndá ènìyàn ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Adelé alága àjọ náà, Florence Austin ni ó pe ìpè náà nínú ọ̀rọ̀…
Ìgbìmọ̀ Fún Ètò Ìlera Ní Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ti Mú Ìgbéga Bá Ilé Ìwòsàn Ìjọba…
Ìgbìmọ̀ Fún Ètò Ìlera ní Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin ti kéde mímú ìgbéga bá ilé ìwòsàn ìjọba àpapọ̀ tí ó wà ní ìlú Ọwọ, tí yóò sì di ilé ìwòsàn fún ilé ìwé gíga Yunifásitì
Alága ìgbìmọ̀…
Red Cross túnbọ̀ fẹsẹ̀ ìpinnu rẹ̀ múlẹ̀ láti pèsè ìgbé ayé tó dárá lágbègbè
Ẹgbẹ́ Red Cross ti Naijiria (NRCS) ti túnbọ̀ fẹsẹ̀ ìpinnu rẹ̀ múlẹ̀ láti mú ìgbé ayé agbègbè dára lorilẹ-ede.
Ẹgbẹ naa, pẹlu ajọṣepọ pẹlu ẹgbẹ Red Cross ti British(BRC), sọ pe wọn ti sọ nipa igbesilẹ awọn ohun itura ni awọn…