Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌLERA
This is a category for health news
Àwọn Onímọ̀ Gba Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Làmọ̀ràn Láti Ṣe Ìtọjú Ọpọlọpọ Wọn.
Oníṣègùn nípa ọpọlọ tí ile ìwòsàn ìjọba ni Yaba ni ìlú Eko Dọ́kítà Olugbenga Owoeye ti gbà àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíría Làmọ̀ràn láti ma lo fún àyẹwò ipò tí ọpọlọ wọn wà lore kore, ti o ba nilo iranlọwọ
Àmọ̀ràn yìí jáde nígbà tí Ààrẹ…
Aṣòfin Bayelsa Pinnu láti kojú ìlòkulò òògùn ní ìpínlẹ̀
Aṣòfin tí ń ṣojú agbègbè ìjọba àpapọ̀ Gúsù Ijaw, ti ìpínlẹ̀ Bayelsa, Aṣojú onímọ̀-ẹ̀rọ Rodney Ambioiwei ti sọ pé òun fẹ́ ṣe onígbọ̀wọ́ àbá àti òfin ìlòkulò òògùn. Ó ń sọ èyí níbi ìfọ̀rọ̀wánilẹnuwò kan ní…
Ẹka Ètò Ìlera Ní Ìpínlẹ Kaduna Ti Pàrowà Sí Ará Ìlú Láti Gba Ìtọ́jú Ní Ààyè Tí…
Alákòóso Ètò Ìlera ní Ẹka Ètò Ìlera Ìpínlẹ̀ Kaduna, Dókítà Sadiq Idris ti pàrọwà sí ará ìlu láti se àmójútó ìlera ara wọn, kí wọ́n sì rí i dájú pé wọ́n gba ìtọ́jú ní ààyè tí ó tọ́
Idris…
Àjọ Ọmọ Ológun Sàgbékalẹ̀ Àyẹ̀wò Ọ̀fẹ́ Fún Àwọn Ènìyàn Àgbègbè Ikorodu
Alákòóso Àjọ Ọmọ Ogun, Odoguyan, Ìlú Èkó, Ọ̀gágun Muhammad Abdurrahaman ti gba àwọn ènìyàn àgbègbè Ikorodu níyànjú ní ọjọ́ Àbámẹ́ta láti jìnà sí ìwà ti ́ o le è da omi àlàáfíà ìlú ru, kí wọ́n sì lo…
Awọn Tọrọ kàn Gbé Òsùbà O Káre Fún Àjọ AU Lórí Ìtọ́jú Ọfẹ Nípa Àìsàn jẹjẹrẹ Ẹ̀dọ̀ Ni Ìpínlẹ̀…
Àwọn Òṣìṣẹ́ tọrọ kàn nipa ìtọ́jú Ìlera tí ìpínlẹ̀ Nasarawa Gbóríyìn fún Àjọ AU ati awọn àjọ tó bá wọn ṣiṣẹ pọ láti leè rí wí pé àìsàn jẹjẹrẹ ẹ̀dọ̀ di ohun igbagbe láwùjọ àti ní ìpínlẹ̀ Nasarawa.
Adarí àgbà pátápátá fún ètò ìlera ní ilé…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Enugu Jẹ́jẹ̀ẹ́ Láti Pèsè Ilé Ìwòsàn Alábọ́dé Lọ́pọ̀ Yanturu
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Enugu ti jẹ́jẹ̀ẹ́ láti pèsè Ọ̀tàlélúgba ilé ìwòsàn alábọ́dé jákè-jádò ìpínlẹ̀ náà
Gómìnà Peter Mbah sísọ lójú ọ̀rọ̀ náà nígbà tí ó ń se àbẹ̀wò ilé ìwòsàn alábọ́dé ní…
Àjọ Àgbáyé Kan Ti Fi Ìgbáradì Rẹ̀ Hàn Láti Pèsè Àwọn Ohun Èlò Tí Ó Se Pàtàkì Fún…
Àjọ àgbáyé kan tí ó n rí sí ìgbáyégbádùn àwọn ènìyàn tí ó ń ṣí kiri láti ìletò Kan lọ sí òmíràn ti fi ìpinnu àti ìgbáradì rẹ̀ léde láti pèsè ohun èlò tí ó péye fún àwọn tí ó kù díẹ̀ kààtó…
Àjọ NCDC Gbe Ìgbésẹ̀ Ọ̀tun Láti Dènà Ìtànkálẹ̀ Àrùn Ní Àwùjọ
Alákòóso Àgbà Fún Àjọ NCDC, Dókítà Ifẹdayọ Adetifa ti gbé ìgbésẹ̀ akin lójúnà àti dènà ìtànkálẹ̀ àrùn jákè-jádò Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Ó sísọ lójú ọ̀rọ̀ náà níbi àpérò kan tí ó wáyé…
Ojúse Àwọn Ọba Alayé, Olórí Ẹ̀sìn Se Pàtàkì Fún Ìdàgbàsókè Ètò Ìlera- Ìjọba…
Mínísítà Fún Ètò Ìlera Àti Ìgbáyégbádùn Ọmọnìyàn, Ọ̀jọ̀gbọ́n Muhammad Ali Pate ti sàfihàn pàtàkì ojúse àwọn ọba alayé àti àwọn olórí ẹ̀sìn nínú ìtẹ̀síwájú ètò ìlera ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà…
Àwọn Òògùn Tí Kò Tọ́ : Gomina Uzodinma Gbà Àwọn Ọ̀dọ́ Làmọ̀ràn Láti Tẹ̀lé Ọ̀nà Tó Tọ́ Lórí Lilọ…
Gómìnà ìpínlẹ̀ Imo Hope Uzodinma tí gbà àwọn ọ̀dọ́ Làmọ̀ràn láti yẹra fún àwọn Oògùn tí kò gba ọ̀nà òfin jáde ki wọn sì gbà ọ̀nà tí o tọ fún lílò oògùn
Gómìnà mú àmọ̀ràn yìí wa níbí ìdánilékọ̀ọ́ lori lílo oògùn tí àjọ NDLEA àti ilé iṣé…