Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌLERA
This is a category for health news
Mínísítà Rọ Àwọn Tó N tọmọ Lọwọ Láti Ri Wí Pé Wọn Fún Àwọn Ọmọ Wọn Ni Ọmú Àti Abẹ́rẹ́ Àjẹsára.
Mínísítà fún ìpínlẹ̀ ni Ìlú Abuja Dọ́kítà Mariya Bunkure ti rawọ ẹgbẹ́ sí àwọn Obìnrin tó n tọmọ Lọwọ láti rí wí pé wọn fún àwọn ọmọ wọn ní ọmú àti abẹ́rẹ́ àjẹsára láti lè dènà àwọn àìsàn tí yóò ṣe àkóbá fún ìlera àwọn ọmọ wọn.
Ó sọ èyí…
Àwọn Ènìyàn Ìlú Abuja Pé Fún Ìrànlọ́wọ́ Nípa Owó Ìtọ́jú Ti Wọn N Ná Ni Ilé Ìwòsàn
Àwọn ènìyàn ìlú Abuja ti pé ìjọba àpapọ̀ láti sí jú àánú wọn àwọn ènìyàn ìlú Abuja nípa owó tí wọn ń san fún ìtọ́jú ni ilé ìwòsàn.
Nínú ìfòròwánilénuwò pẹ̀lú àwọn ènìyàn ìlú Abuja ní ọ̀rọ̀ náà tí jáde ní ọjọ́ ajé lásìkò ayẹyẹ ajoyọ ọdún…
Ewé Moringa Leè Pèsè Iṣẹ́ Fún Àwọn Ènìyàn Ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà:Akoloaga.
Dọ́kítà Ashimashiga Michael Akoloaga, to jẹ Olùdásílẹ̀ ilé iṣé Eden Group ti sọ wí pé ewe ti wọn mọ sí Moringa Value Chain ti agbára rẹ tó 77,400 láti mú kí àwọn ènìyàn ni isé lọ́wọ́, o ni pẹ̀lú àwọn ànfààní míràn tó sọ mọ.
Ilé iṣé Eden…
Gómìnà Soludo ṣe ìfilọ́lẹ̀ ilé ìwòsàn tuntun ní ìpínlẹ̀ Anambra
Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀jọ̀gbọ́n Chukwuma Charles Soludo ti ṣí ilé ìwòsàn tuntun kan tí ẹgbẹ́ àwọn ọmọ abínibí Anambra tó wà ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà kọ́ fún èlò ìpèsè ìwòsàn fún àwọn arah ìlú.
Lasiko…
Ilé iṣẹ́ kan ní Ondo gbé àwọn èròjà oúnjẹ lọ sí ilé àwọn ọmọ aláìlóbìí
Ilé iṣẹ́, Ondo-Lynyi Industry Limited, ní ìjọba ìbílẹ̀ Odigbo, agbègbè ìpínlẹ̀ Ondo ti gbé àwọn oun èlò oúnjẹ lọ sí ilé àwọn ọmọ aláìlóbìí ní ìpínlẹ̀ náà. Àwọn ọmọ ilé ọmọ tí kò lóbìí tó ju àádọ́ta…
Ìjọba ìpínlẹ̀ Nasarawa gbé ìgbésẹ̀ láti dènà àjàkálẹ̀ ààrùn
Ìjọba ìpínlẹ̀ Nasarawa ti sọ pé òun ti ń gbé ìgbésẹ̀ oríṣiríṣi láti ṣàtúnṣe lórí ìpeniníjà tí ń kojú ìpínlẹ̀ náà.
Oluṣakoso gbogbogboo, GM ile iṣẹ ti n daabobo ayika ni Nasarawa, Onimọ Ẹrọ Yusuf Adeka, ṣalaye…
Àjọ Kan Tí Kìí Se Ti Ìjọba Se Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Fún Àwọn Ọ̀dọ́mọbìnrin Ní Ìpínlẹ̀ Bauchi
Àjọ Aládàníi kan ti se ìdánilékọ̀ọ́ fún àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin ní ìpínlẹ Bauchi lórí ìmọ́tótó, ẹ̀tọ̀ ọmọbìnrin, àti ìlanilọ́yẹ̀ kúrò níbi lílo ọmọnìyàn ní ìlò ẹrú
Agbẹjọ́rò kan tí ó fi ìlú Bauchi se…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Imo Gba Àwọn Ọ̀dọ́ Níyànjú láti Jìnà Sí Àsìlò Òògùn Àti Ìwà…
Ìjọba ìpínlẹ̀ Imo ti se ìkìlọ̀ fún àwọn ọ̀dọ́ láti jìnà sí ìwà àsìlò òògùn ati ìwà ọ̀daràn lásìkò ọdún tuntun
Olùbádámọ̀ràn pàtàkì sí Gómìnà Uzodinma lórí Ọ̀rọ̀ Òògùn lílò, Olóyè…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ògùn Se Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Fún Àwọn Ènìyàn Ìpínlẹ̀ Náà Lórí Ìtànkálẹ̀…
Àjọ tí ó ń pèsè Omi àti Ìmọ́tótó Àyíká ní ìpínlẹ̀ Ogun ti bẹ̀rẹ̀ ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lójúnà àti dènà ìtànkálẹ̀ àrùn onígbáméjì àti àwọn irúfẹ́ àrùn bẹ́ẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ogun
Kọmísọ́nà Fún…
Ìpínlẹ̀ Katsina: Ẹgbẹ́ Ni Àwọn Lòdì Sí Àsìlò Ògùn Láàrin Àwọn Ọmọdé Àti Obìnrin.
Àwọn ẹgbẹ́ to n mójú tó ọ̀rọ̀ àwọn ará ìlú ní ìpínlẹ̀ Kastina sọ wí pé àwọn lòdì sí bí àwọn Obìnrin àti ọmọdé se n sí Ògùn lò.
Alága fún ẹgbẹ́ náà Alhaji Amoni Abubakar -Danmusa sọ wí pé o jẹ ọ̀nà ti kò bá ojú mu tó láti rí pé àwọn ọmọdé…